Categories
Ìròyìn

Àtíkù Kò Lè Díje Fún Ipò Ààrẹ, Kìí Ṣe Ọmọ Nàíjíríà – Malami

YBTC News YORÙBÁ—  Agbẹjọ́rò gbogbo-gbòò fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Abubakar Malami ti sọ fún ilé ẹjọ́ ńlá tí ó kalẹ̀ sí Abùjá wípé igbákejì ààrẹ ní ìgbà kan rí, Àtíkù Abubakar kò lee díje sí ipò ààrẹ. Ẹ ó rántí wípé ní ọdún 2019, àjọ kan tí orúkọ rẹ̀ń jẹ́ EMA gbé Àtíkù lọ sí ilé […]

Categories
Ìròyìn

Atiku Sọ Ìdí Tí A Gbọdọ̀ Fi Ṣe Àtìlẹyìn Fún Buhari Fún Àṣeyọrí Rẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan, tí ó tún jẹ́ olùdíje sí ipò ààrẹ 2019,fún ẹgbẹ́ PDP, Alhaji Atiku Abubakar ti sàlàyé ìdí tí a gbọ́dọ̀ fi ṣe atìlẹyìn fún ààrẹ Buhari. Atiku ṣàlàyé oríṣìíríṣìí ìmọ̀ràn tí òun àti àwon ènìyàn míìràn tí gba ìṣèjọba ààrẹ Buhari ṣùgbọ́n tí wọn kọ etí […]