Categories
Ìròyìn

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Oyo, Seyi Makinde Lu Gbẹ́dẹ Àrùn Coronavirus

Seyi Makinde, gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo pẹ̀lú àwọn tí wọ́n ti lu gbẹ́dẹ àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Gómìnà náà fi ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun náà lédè lórí ẹ̀rọ alátagbà rẹ̀, ìyẹn Twitter ní ọjọ́ ajé. Gómìnà náà wá rọ àwọn ará ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ wípé kí wọ́n tẹ́lẹ̀ gbogbo ìlànà tí àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ elétò ìlera […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Mẹ́fà Kan Tí Wọ́n Lu Gbẹ́dẹ Àrùn Coronavirus Ni Àyẹ̀wọ̀ Fi Hàn Báyìí Wípé Wọn Kò Ní Àrùn Náà Mọ́

YBTC News Yorùbá-Olùbáni Dámọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ ìlera fún gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn Dókítà Tunde Ajayi ti sọ fún àwọn oníròyìn wípé àwọn mẹ́fà lára àwọn tí ó lu gbẹ́dẹ àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus ní ara wọn ti yá báyìí. Ajayi lórí ẹ̀rọ alátagbà rẹ̀, ìyẹn Twitter ní ọjọ́ ọjọ́bọ sọ pé àwọn mẹ́fà nínú àwọn […]

Categories
Ìròyìn

Àyẹ̀wọ̀ Fihàn Kedere Wípé Ọmọ Ilẹ̀ Ìtàló Tí ó Kó Coronavirus Wọ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà Kòní Àrùn Náà Lára Mọ́

YBTC News Yorùbá-Komíṣọ́nà fún ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn Ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Ayobami tí sọ pé ọmọ orílẹ̀ èdè Ìtàló tíó kó àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus wọ orílẹ̀ èdè yìí ni àyẹ̀wọ̀ ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé kò ní àrùn náà lára mọ́. Ó sọ eléyìí nìdí ìbánisọ̀rọ̀ tí ó bá àwọn oníròyìn ṣe ní […]

Categories
Ìròyìn

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Kéde Àwọn Ènìyàn Mẹ́rin Ti Titun Tí ó Ní Àrùn Coronavirus

YBTC News Yorùbá-Komíṣọ́nà fún ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn Ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Ayobami tí sọ pé àwọn ènìyàn mẹ́rin tuntun míràn ti ní àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus ní ìpínlẹ̀ Èkó báyìí. Ní ọjọ́ ọjọ́rú nígbà tí ó ń bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ lórí oun tuntun tí ó ti ń ṣẹlẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ àrùn kòkòrò corona, […]

Categories
Ìròyìn

Arìnrìn-àjò Kan Ti Kú Ní Orílẹ̀ Èdè Egypt Látàrí Àrùn Coronavirus, Ó Jẹ́ Ẹni Àkọ́kọ́ Tí Kòkòrò Náà Ma Pa Ní Ilẹ̀ Áfíríkà

YBTC News Yorùbá-Arìnrìn-àjò kan ọmọ orílẹ̀ èdè Jamaní ti pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ sí ọwọ́ kòkòrò Coronavirus ní ayé ìgbafẹ́ Sinai ní ìlà oòrùn Egypt. Gẹ́gẹ́bí ilé iṣẹ́ ètò ìlera orílẹ̀ èdè náà ṣe kéde, arìnrìn-àjò náà jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí kòkòrò náà ma kọ́kọ́ gba ẹ̀mí rẹ̀ ní ilẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú. Ọmọ ọgọ́ta ọmọ orílẹ̀ […]

Categories
Ìṣẹjúkan àti Àbọ̀

Àwọn Ọ̀nà Tí a Lè Gbà Dènà Ìtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Ní Àwùjọ Wa Rèé

Àwọn Ọ̀nà Tí a Lè Gbà Dènà Ìtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Ní Àwùjọ Wa Rèé Kí a ma fọ ọwọ́ wa dáadáa pẹ̀lú omi ẹnu ẹ̀rọ tí ó ń jáde tààrà. Kí a sì ma lo ọṣẹ kòkòrò tí ó ní ọtí nínú láti ma fi fọwọ́ wa. Kí o máa lo ìbọ̀wọ́ kan nígbà kan, […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àjọ Ọlọ́pàá Fi Ọwọ́ Ṣùkún Òfin Mú Àwọn Márùn-ún Kan Tí Wọ́n Dẹmọ Wípé Àwọn Ní Àrùn Coronavirus

YBTC Yorùbá –Àjọ agbófinró ti olú ìlú wa Abuja ti fi ọwọ́ ṣù kún òfin mú àwọn márùn-ún kan tí wọ́n dẹmọ wípé àwọn ti sagbako àrùn aṣeni básubàsu tí ó pànìyàn kiri káàkiri àgbáyé. Àwọn Márùn-ún yìí ni wọ́n fi ẹ̀sùn kàn wípé wọ́n yawọ ilé ìwòsàn ńlá kan tí ó wà ní Wuse, […]