Categories
Eré Ìdárayà

Ìdí Rèé Tí Mofi Fi Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Arsenal Sílẹ̀ – Ajayi Lahùn

YBTC News Yorùbá-Agbábọ́ọ̀lù nípò ẹ̀hìn fún ikọ̀ West Brom ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn Semi Ajayi ti ṣàlàyé fún àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ìdí tí òun fi fi Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú Arsenal sílẹ̀ lọ sí Ikọ̀ míràn lẹ́yìn sáà igbábọ́ọ́lù méjì péré. Ajayi sọ pé òun ń wá Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú tí ó jẹ́ wípé òun ma […]

Categories
Eré Ìdárayà

Àwọn Agbábọ́ọ̀lù Ikọ̀ Arsenal Wà Ní Ìyàrá Àyẹ̀wọ̀ Lórí Ọ̀rọ̀ Coronavirus, Wọ́n Sún Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Síwájú

YBTC News Yorùbá-Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí ó yẹ kí Ikọ̀ Arsenal ti orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì gbá ní ọjọ́ ọjọ́rú ní wọ́n ti sún síwájú látàrí bí gbogbo agbábọ́ọ̀lú Ikọ̀ náà ṣe wà ní ìyàrá àyẹ̀wọ̀ fún àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus. Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n ma sún ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ síwájú lórí lẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì láti ìgbà tí […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ikọ̀ Arsenal Tí ń Gbìyànjú Láti Kówólé Agbábọ́ọ̀lù Àdehìnmú Flamingo Bí Iná Ikọ̀ Náà Ṣe ń Jó Àjórẹ̀hìn

YBTC Yorùbá- Arsenal ń gbìyànjú láti tọwọ́ agbábọ́ọ̀lú Flamingo tí ó jẹ́ Àdehìnmú fún ikọ̀ náà, ìyẹn Pablo Mari bí ó ṣeéṣe kí agbábọ́ọ̀lú náà má padà sí orílẹ̀ èdè Brazil. Mari wá sí ìlú Olú ìlú ilé Gẹ̀ẹ́sì, London fún Àyẹ̀wọ̀ ìlera ara rẹ̀ ní ikọ̀ Arsenal. Ìròyìn fìdí rẹẹ̀ múlẹ̀ wípé Ikọ̀ Arsenal […]

Categories
Eré Ìdárayà

Àwọn Olólùfẹ́ Ikọ̀ Arsenal Á Maa Dẹ́rùbani – Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Arteta Sọ̀rọ̀ Bí Ikọ̀ Náà Ṣe Ta Ọ̀ọ̀mì Pẹ̀lú Sheffield

YBTC Yorùbá-Mikel Arteta tí ó jẹ́ Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Arsenal nígbàgbọ́ wípé àwọn olólùfẹ́ Ikọ̀ ọ̀ún tí ń móríbọ́ lọ́wọ́ ẹgbẹ́ ọkàn tí Ikọ̀ náà ti kó wọn sí látẹ̀yìn wàá. Arteta tó darapọ̀ mọ́ Ikọ̀ Arsenal ní oṣù tó kọjá ba’ṣẹ́ lọ́wọ́ Unai Emery gẹ́gẹ́bi Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ ọ̀ún, ó sì bá Ikọ̀ ọ̀ún tí ó […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ikọ̀ Arsenal Bu Iyì-Ẹ̀yẹ Fún Kanu Bí Ó Ṣe Pé Ọdún Mọ́kànlélógún Tí Ó Tọwọ́bọ̀wẹ́ Àdéhùn Pẹ̀lú Ikọ̀ Náà

YBTC Yoruba—Kanu Nwakwo tí ó dé adé agbábọ́ọ̀lú tó fakọyọ jùlọ nílẹ̀ Áfíríkà ní ẹ̀meejì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni Ikọ̀ Arsenal ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lọ́ùń ti bu iyì-ẹ̀ye fún lánàá láti fi sààmì ọdún kankànlélógún tí agbábọ́ọ̀lú tí ó ti fẹ̀yìntì náà tọwọ́bọ̀wẹ́ àdéhùn pẹ̀lú Ikọ̀ náà. Àná ọjọ́ ọjọ́rú ní ópé ọdún kankànlélógún tí Ikọ̀ Arsenal […]

Categories
Eré Ìdárayà

Jordan Ayew Gbégi Dínà Ògo Arsenal: Ó Gbá Bọ́ọ́lù Wọnú Àwọ̀n Àlejò Náà Tí Wọ́n Fi Gbá Ọ̀ọ̀mì

YBTC Yorùbá- Jordan Ayew ọmọ ẹgbẹ́ Ikọ̀ Crystal Palace gba ẹ̀yẹ bí ó ṣe gbá bọ́ọ́lù sí àwọ̀n àlejò wọn, ìyẹn Ikọ̀ Arsenal nínú ìfẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ tí wọ́n ní lónìí ọjọ́ àbàmẹ́ta. Ikọ̀ Arsenal tí ń lé iwájú nínú abala àkọ́kọ́ nínú ìfẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ náà pẹ̀lú bí aṣáájú Ikọ̀ náà, ìyẹn Pierre-Emerick Aubameyang ṣe gbá bọ́ọ́lù àkọ́kọ́ […]

Categories
Eré Ìdárayà

Saka Wà Ní Ipò Kẹjọ Nínú Agbábọ́ọ̀lù Tó Lówó Lórí Jùlọ Ní Líígì Orílẹ̀ Èdè Gẹ̀ẹ́sì

YBTC Yorùbá- Ọmọ ológo tí ó wà ní Arsena, Bukayo Saka ni ìròyìn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé ipò kẹjọ ni ó wà nínú agbábọ́ọ̀lú ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́ tí ó níye lórí jùlọ nínú ìdíje àgbákuta líígì ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Ọmọ ọdún méjìdínlógún náà ti jẹ́ ìfihàn láti ìgbà tí ó ti kópa nínú ìfẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ tí Ikọ̀ […]

Categories
Eré Ìdárayà

Arsenal Ṣe Bẹbẹ Lánàá, Ó Fi Ẹ̀yìn Man U Gbolẹ̀ Yánayàna

YBTC Yorùbá- Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú Arsenal dójú ti àwọn alátakò rẹ̀ lánàá bí ó ṣe fi ẹ̀yìn àlejò rẹ̀, ìyẹn Manchester United gbolẹ̀ yánayàna. Ayò Méjì sí óódo ni Arsenal fi gbẹ̀yẹ lọ́wọ Manchester United. Ṣáájú àsìkò yìí ni ẹnu tí ń kun Ikọ̀ Arsenal lóri bí iná Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú náà ṣe ń jó rẹyìn nínú […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ikọ̀ Arsena Ní Láti Ṣe Àtúnṣe Sí Ìbáṣepọ̀ Tí ó Wà Láàrin Ikọ̀ Náà Àti Àwọn Olólùfẹ́ Wọn – Mikel Arteta

YBTC Yorùbá- Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá tuntun fún ikọ̀ Arsena, Ọ̀gbẹ́ni Mikel Arteta ti ní ó pọn dandan báyìí fún ikọ̀ Arsena láti so okùn ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàrin Ikọ̀ ọ̀ún àti àwọn olólùfẹ́ wọn. Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá tuntun náà ṣàlàyé wípé bí Ikọ̀ náà bá lè dáná ìyà fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú Chelsea, yóò mú àwọ̀ tuntun bá Ikọ̀ […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Arsenal Gba Àlejò Ọ̀ràn Lánàá, Mẹ́ta Sí Òdo Ni Ó jẹ Ní Ọwọ Man. City

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú Arsenal fìdí rẹmi ní ilé wọn lánàá nígbà tí wọ́n gba ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú Machester City ní àlejò nínú ìdíje líígì ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Àlùbámi ni àlejò Machester City náà fi onílé Arsenal ṣe nígbà tí ó báa lálejò ní pápá ìseré Emirate. Ayò mẹ́ta sí òdo ni Machester City fi ṣe ìyà fún Arsenal […]