Categories
Eré Ìdárayà

Ancelotti Ní Ikọ̀ Everton Nírètí Láti Kópa Nínú Ìdíje Europa Líígì Lẹ́yìn Tí Ikọ̀ Náà Fẹ̀yìn Crystal Palace Gbolẹ̀ Yánayàna

YBTC Yorùbá- Ipò Ikọ̀ Everton sún sókè lọsí ipò keje nínú líígì ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì bí Ikọ̀ náà ṣe fẹ̀yìn Crystal Palace gbolẹ̀ yánayàna ní ọjọ́ àbàmẹ́ta, ayò mẹ́ta sí ẹyọkan ni Everton fi fi àgbà han Ikọ̀ ọ̀ún. Bernard, Richarlison, àti Dominic Calvert-Lewin ni ó gbá àwọn bọ́ọ́lù mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọn nú àwọn fún ikọ̀ Everton. […]