Categories
Ìròyìn

Ìdásílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn Ti Jẹ́ Kó Di Dandan Láti Gúnle Àtúntò Ètò Ìṣèjọba Ní Orílẹ̀ Èdè Yìí – Dickson

YBTC Yorùbá- Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bayelsa, Seriake Dickson ti sọ̀rọ̀ lórí ìdásílẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn, èyí tí àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà dá sílẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ àbò tí ó mẹ́hẹ ni agbègbè wọn, Dickson ní ìdásílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn ti sọ́di dandan fún wa ní orílẹ̀ èdè yìí láti ṣe àtúntò ètò ìsèjoba orílẹ̀ èdè yìí. […]

Categories
Ìròyìn

Àwa Ò Ní Ẹ̀yà Kankan Lọ́kàn Kí a Tó Dá Àmọ̀tẹ́kùn Sílẹ̀ – Àwọn Gómìnà Ìwọ̀ Oòrùn Gúúsù Ṣàlàyé

YBTC Yorùbá-Alága àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó tún jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ondo, Arákùnrin Rotimi Akeredolu ti fi ọkàn àwọn ọmọ Nàìjíríà balẹ̀ lórí ẹ̀ṣọ́ aláàbò tuntun tí wọ́n dá sílẹ̀, ìyẹn Àmọ̀tẹ́kùn. Akeredolu lánàá ọjọ́ àìkú ṣàlàyé wípé àwọn Gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù náà kò ní èrò ǹgbà láti gbógun ti […]

Categories
Ìròyìn

Adebanjo, Okunronmu àti Àwọn Yòókù Dìgbòlu Tinubu Bí ó Ṣe Dákẹ́ Lórí Ọ̀rọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn

YBTC Asíwájú àgbà nínú ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re, ìyẹn Pa Ayo Adebanjo àti Aṣòfin Femi Okunronmu ní ọjọ́ àbàmẹ́ta sọ̀rọ̀ kùgbákùgbé sí Asíwájú àgbà nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), ìyẹn Asiwaju Bola Tinubu bí ó ṣe kùnà láti sọ̀rọ̀ lórí Àmọ̀tẹ́kùn. Ṣùgbọ́n agbẹnusọ fún Asiwaju Tinubu sọ wípé àsìkò kò ì tìí tó ló fà […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àpapọ̀ Ẹgbẹ́ Amòfin Ilẹ̀ Nàìjíríà Ti Bu Ẹnu Àtẹ Lu Amòfin Àgbà Ilẹ̀ Yìí Lóri Ipò Rẹ̀ Lórí Àmọ̀tẹ́kùn

YBTC Yorùbá- Àjọ ẹgbẹ́ àpapọ̀ Aṣòfin ilẹ̀ yìí, ìyẹn Nigeria Bar Association (NBA) ti bu ẹnu àtẹ lu ọ̀rọ̀ tí amòfin àgbà ilẹ̀ yìí tí ó tún jẹ́ Mínísítà fún ètò Ìdájọ́, ìyẹn Abubakar Malami (SAN) sọ wípé ìdàsílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn kò b’ófinmu. Àwọn Amòfin náà sọ̀rọ̀ yìí láti ẹnu agbẹnusọ gbogbogbò ẹgbẹ́ náà, ìyẹn Ọ̀gbẹ́ni […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àwọn Ẹgbẹ́ Kan Ti Fún Tinubu Ní Wákàtí Méjìlélógún Láti Fi Ìpínnu Rẹ̀ Hàn Lórí Àmọ̀tẹ́kùn

YBTC Yorùbá-Àwọn ẹgbẹ́ kan ni Ìwọ̀ Oòrùn Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ti amọ̀sí Save Lagos Group ti fún Alága Abẹ́lé nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), Asiwaju Bola Tinubu ni gbèdéke wákàtí méjìlélógún láti fi fi èrò rẹ̀ hàn sí àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí Àmọ̀tẹ́kùn. Tinubu tí àwọn ènìyàn rí bi asíwájú ní Ìwọ̀ Oòrùn […]

Categories
Ìròyìn

Afẹ́nifẹ́re Sọ Jágbajàgba Ọ̀rọ̀ Sí Malami, Wọ́n Ní Ọ̀rọ̀ Burúkú Ní Mínísítà Nsọ Nígboro Ẹnu

Ẹgbẹ́ ajá fún ẹ̀tọ́ ti àwọn Ọmọ Yorùbá tí a mọ̀ sí Afẹ́nifẹ́re ti sọ jágbajàgba ọ̀rọ̀ sì amòfin àgbà ilẹ̀ yìí tí ó tún jẹ́ Mínísítà fún ètò Ìdájọ́, ìyẹn Abubakar Malami (SAN) lórí ọ̀rọ̀ tí Mínísítà náà sọ wípé ìdàsílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn kò b’ófinmu. Alága gbogbogbò ẹgbẹ́ gbẹ́ náà, Olóyè Olawale Oshun ní ọ̀rọ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Gómìnà Ilẹ̀ Yorùbá Ti Ń Gbìyànjú Láti Ṣe Ìpàdé Pò Pẹ̀lú Ààrẹ Buhari Lórí Ọ̀rọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn

Alamí ti ń tó àwọn oníròyìn létí báyìí wípé àwọn Gómìnà ìwọ oòrùn gúúsù ti ń gbìyànjú láti ṣe ìpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Muhammadu Buhari lóri bí ìjọba àpapọ̀ ṣe kéde Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn gẹ́gẹ́ bíi Ẹ̀ṣọ́ tí kò bófin mu. A gbọ́ wípé ìpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Buhari náà ma wáyé lèyín tí àwọn gómìnà náà […]

Categories
Ìròyìn

Àmọ̀tẹ́kùn: Àwọn Ọmọ Yorùbá Ṣe Tán Láti Gbé Pẹ́rẹ́gi Ìjà Kaná Pẹ̀lú Ìjọba Àpapọ̀ Bí ó Kéde Pé Àmọ̀tẹ́kùn Kò Bófin-mu

YBTC Yorùbá-Agbẹjọ́rò Àgbà ní orílẹ̀ èdè yìí tí ó tún jẹ́ Mínísítà fún ètò Ìdájọ́ Ilẹ̀ yìí, ìyẹn Abubakar Malami kéde láìpẹ́ yìí wípé Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ oòrùn gúúsù ṣe ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní ọ̀sẹ̀ tí ó kọjá kò bá òfin mu. Òye tí ń fojú hàn wípé àwọn gómìnà náà ti […]

Categories
Ìròyìn

Àmọ̀tẹ́kùn: Ẹ Gbé Ìbọn Dánì Lọ́nà Aitọ́, Kí ẹ Fi Ojú Winá Òfin – Ọlọ́pàá Ṣèkìlọ̀ Fún Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́ Òòduà àti Ọlọ́dẹ

YBTC Yoruba—Àjọ àwọn Ọlọ́pàá ti ṣèkìlọ̀ fún gbogbo àwọn tí ọ̀rọ̀ kọ́ọ̀n lórí ẹ̀ṣọ́ aláàbò tuntun tí àpapọ̀ gómìnà Ìwọ̀ Oòrùn Gúúsù ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ láti sọra níbi à ń lo oun èròjà àbò lọ́nà tí ò bófin mú. Ẹ̀ka Ọlọ́pàá ti ìpínlẹ̀ Ekiti, Ondo àti Ogun ṣàlàyé fún àwọn oníròyìn wípé àwọn kòní fi […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àwa Kò Nígbà Kí Àmọ̀tẹ́kùn Tẹ Ẹ̀tọ́ Wa Mọ́lẹ̀, Ẹgbẹ́ Fúlàní Darandaran Léríléka

Àjọ ẹgbẹ́ Fúlàní darandaran nílẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ ìṣàkoso wọn tí a mọ̀ sí Miyetti Allah Kautal Hore ti fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn lórí ìfilọ́lẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ oòrùn gúúsù ṣe ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ ọjọ́bọ. Ẹgbẹ́ Fúlàní Darandaran náà ṣe ìkìlọ̀ wípé àwọn kòní lajú lè kí àwọn Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò […]