YBTC News Yorùbá-Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ìyẹn Seyi Makinde ní ọjọ́ ìṣẹ́gun wọ aṣọ aláwọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn láti buwọ́lu ìwé òfin tí ó ma ṣe ìdásílẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò àgbègbè ní ìpínlẹ̀ náà, léyìí tí ó ma ṣe ìdásílẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ oòrùn gúúsù ṣe ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní àìpé yìí. Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ìpínlẹ̀ […]
