Categories
Ìròyìn

Àmọ̀tẹ́kùn Àti Miyetti Allah Ṣe Ìpàdé Ní Ọ̀sun. Ẹ Wo Àbájáde Ìpàdé

YBTC News YORÙBÁ— Ẹ̀ṣọ́ àbò ilẹ̀ Yorùbá, Àmọ̀tẹ́kùn ti ẹka ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni ìròyìn ti gbé e wípé wọ́n jọ ń ṣe ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn Miyetti Allah fún bí ètò ọrọ̀ àbò ìpínlẹ̀ náà yóò ṣe dára. Àwọn àkójọpọ̀ ilẹ̀ Yorùbá kan tí wọn pè ní “Kiriji Heritage” to fi ẹ̀hónú ọkàn wọn lánàá […]

Categories
Ìròyìn

Wọlé Sóyínká Ti Di Baba Ìsàlẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn Ìpínlẹ̀ Ògùn

YBTC News YORÙBÁ—  Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Sóyínká, ẹni tí ó fìgbà kan rí gbà oyè gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó dáńtọ́ jùlọ nínú Lítíréṣọ̀ Gẹ̀ẹ́sì àgbáyé ni ọdún 1986.Fidioq Sóyínká ni wọn fi joyè níbi ìfilọ́lẹ̀ ikọ̀ Amọtẹkun gẹ́gẹ́ bí baba ìsàlẹ̀ ikọ̀ náà. Gómìnà Abíọ́dún gbé àwọn àwòrán ìfilọ́lẹ̀ náà sí orí ẹ̀rọ ayárabíàsá rẹ̀. […]

Categories
Ìròyìn

Àmọ̀tẹ́kùn Tí Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Ní Ògùn

YBTC News YORÙBÁ—Ikọ̀ ẹ̀ṣọ́ aláàbò ti abẹ́lé ní ìpínlẹ̀ Ògùn, Àmọ̀tẹ́kùn ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ náà ní Ọjọ́’bọ̀ láti lè fi òpin sí ìpèníjà tí ń kọjú ètò ààbò ní ìpínlẹ̀ náà bíi jíjí ènìyàn gbé, ìfipábánilòpọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ikọ̀ náà tí David Akínrẹ̀mí, ọ̀gá ọlọ́pàá tó ti fẹ̀yìn tì jẹ́ olórí […]