Categories
Ìròyìn

Ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re Wípé Àwọn Ò Sọ Pé Àwọn Gbé Tinúbú Lọ́wọ́ Fún Ààrẹ 2023

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ àkójọpọ̀ àwọn ọmọ Yorùbá àtàtà, Afẹ́nifẹ́re ti fohùn ráńṣẹ́ sí gbogbo ọmọ Nàíjíríà wípé àwọn kọ́ ni àwọn sọ pé àwọn ti fi ẹnu kò mú Tinúbú gẹ̀gẹ́ bí ààrẹ wọn ọdún 2023. Ẹ rántí wípé adarí àwọn ìdàgbàsókè ọmọ ilẹ́ Yorùbá kan, Ọmọọba Dayo Adéyẹyè sọ wípé àwọn ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re […]

Categories
Ìròyìn

Agbẹnusọ Fún ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re, Yinka Odumakin Ti Jáde Láyé

YBTC News YORÙBÁ—  Agbenusọ fún ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re ilẹ̀ Yorùbá, Yínká Odùmákin ti papò dà ní ilé ìwòsan ńlá olùkọ́ni tí ó wà ní ìlú Èkó lẹ́yìn àìsàn ráńpẹ́. Ìyàwó rẹ̀, ìyáàfin  Joe Okei-Odumakin ló sọ èyí di mímọ̀ ní òní ọjọ́ Àbámẹ́ta. Olóògbé Odùmákin ṣe gudugudu méje yàyà méfà fún ìdàgbàsókè Yorùbá. Pàápàá jùlọ ní […]