Categories
Ìròyìn

Àtíkù Kò Lè Díje Fún Ipò Ààrẹ, Kìí Ṣe Ọmọ Nàíjíríà – Malami

YBTC News YORÙBÁ—  Agbẹjọ́rò gbogbo-gbòò fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Abubakar Malami ti sọ fún ilé ẹjọ́ ńlá tí ó kalẹ̀ sí Abùjá wípé igbákejì ààrẹ ní ìgbà kan rí, Àtíkù Abubakar kò lee díje sí ipò ààrẹ. Ẹ ó rántí wípé ní ọdún 2019, àjọ kan tí orúkọ rẹ̀ń jẹ́ EMA gbé Àtíkù lọ sí ilé […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Èmi Ò Sọ Wípé Àmọ̀tẹ́kùn Ò B’ófinmu, Àwọn Ènìyàn Ló Ṣìmí Gbọ́ – Malami Kọ́rọ̀ Rẹ̀ Jẹ

YBTC Yoruba—Amòfin Àgbà ní orílẹ̀ èdè yìí tí ó tún jẹ́ Mínísítà fún ètò Ìdájọ́, ìyẹn Abubakar Malami ti sẹ́ ọ̀rọ̀ tí ó sọ tẹ́lẹ̀ rí wípé ìdàsílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀ kò sí lábẹ́ òfin. Malami ṣàlàyé ọ̀rọ̀ yìí nígbà tí ó ń dáhùn ìbéèrè […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Gómìnà Ilẹ̀ Yorùbá Ti Ń Gbìyànjú Láti Ṣe Ìpàdé Pò Pẹ̀lú Ààrẹ Buhari Lórí Ọ̀rọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn

Alamí ti ń tó àwọn oníròyìn létí báyìí wípé àwọn Gómìnà ìwọ oòrùn gúúsù ti ń gbìyànjú láti ṣe ìpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Muhammadu Buhari lóri bí ìjọba àpapọ̀ ṣe kéde Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn gẹ́gẹ́ bíi Ẹ̀ṣọ́ tí kò bófin mu. A gbọ́ wípé ìpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Buhari náà ma wáyé lèyín tí àwọn gómìnà náà […]