Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

“Mọ̀ nípa Ọgágun Amao tí Buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ Yàn”(Chief of Air Staff)

“Mọ̀ nípa Ọgágun Amao tí Buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ Yàn”(Chief of Air Staff)-YBTC NEWS YORÙBÁ Air Marshal Isiaka Oladayo Amao, wọ́n bí i ní ojó kẹrinla Oṣù Kẹsàn-án 1965, bíbí àti dàgbà ní Ìpínlè Enugu Gúúsù ìlà oòrùn Nigeria. Lẹ́yìn náà ó lọ sí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun pẹ̀lú àwọn òbí rẹ̀ kì wón tún tó lọ sí ìpínlẹ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Buhari ÓÒ, Ẹ Má Jẹ́kí Bàálù Kankan Wá Sí Orílẹ̀ Èdè Yìí Láti Orílẹ̀ Èdè Tí Coronavirus Bá ń Yọ Lẹ́nu – Atiku

YBTC News Yoruba—Igbá-kejì Ààrẹ ní orílẹ̀ èdè yìí nígbà kan rí, tí ó tún jẹ́ òǹdíje dupò Ààrẹ lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP), ìyẹn Atiku Abubakar ti gba Ààrẹ Muhammadu Buhari lámọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ Coronavirus tí ó wọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́nu lọ́wọ́ lọ́wọ́ yìí. Atiku nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ sọ pé kí […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ààrẹ Muhammadu Buhari Ṣe Ìbẹ̀wò Sí Ìlú Maiduguri Lórí Ọgbọ̀n Èèyàn Tí Boko Haram Pa

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣe ìbẹ̀wò sí ìlú Maiduguri ní ìpínlẹ̀ Bornu láti bá àwọn ará ìpínlẹ̀ náà kẹ́dùn lórí ìṣẹ̀lẹ̀ afẹ̀míṣòfò tí àwọn ẹgbẹ́ afẹ̀míṣòfò alákatakítí ẹ̀sìn Boko Haram ṣe ní ìlú náà láìpẹ́ yìí. Níbi ìkọlù tí àwọn ẹgbẹ́ afẹ̀míṣòfò alákatakítí ẹ̀sìn Boko Haram náà ṣe, èèyàn ọgbọ̀n ni ó fẹ̀mí ṣòfò. […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Buhari Yan Amokachi Gẹ́gẹ́bí Aṣojú Fún Bọ́ọ́lù Gbígbá Lórílẹ̀ Èdè Nàìjíríà

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari ti buwọ́lu agbábọ́ọ̀lú tẹ́lẹ̀ rí fún ilẹ̀ Nàìjíríà, tí ó tún ti gbá bọ́ọ́lù jẹun ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn Daniel Amokachi gẹ́gẹ́bi aṣojú bọ́ọ́lù gbígbá fún orílẹ̀ èdè yìí. Amokachi tí gbogbo wa mọ̀ sí “the Bull” ti gbá bọ́ọ́lù ní ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú àgbà orílẹ̀ èdè yìí, ìyẹn Super […]

Categories
Uncategorized

Buhari, Lawan àti Gbajabiamila Wọlé Ìpàdé Ìdakẹ́rọ́rọ́

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari ti wọ lé ipade pẹ̀lú àwọn olórí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin méjèèjì Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà, Ahmed Lawan àti Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin kékeré, Ọ̀gbẹ́ni Fẹ́mi Gbajabiamila ti wọlé ìpàdé Ìdakẹ́rọ́rọ́ tí ènìyàn kan kò lè ṣàlàyé ìdí ìpàdé náà. Ṣùgbọ́n Alamí fi tó àwọn oníròyìn létí wípé ìpàdé àwọn […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Jonathan Farahàn Ní Aso Rock, Ó Ṣe Ìpàdé Bòńkẹ́lẹ́ Pẹ̀lú Ààrẹ Muhammadu Buhari

YBTC Yorùbá-Ààrẹ àná ní orílẹ̀ èdè yìí, Ọmọwé Goodluck Jonathan ni ó ṣà déédéé yọjú sí ilé ńlá ti ìjọba àpapọ̀ tí a mọ̀ sí Aso Rock ní olú ìlú wa Abuja ní ọjọ́ ọjọ́bọ, tí ó sì ṣe ìpàdé ráḿpẹ́ pẹ̀lú Ààrẹ Muhammadu Buhari. Ìròyìn fidi rẹ̀ múlẹ̀ wípé Ààrẹ àná náà ṣe ìpàdé […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àwọn Ọmọ Rẹ Kò Lẹ́tọ̀ọ́ Láti Sọ Bàálù Ìjọba Ti T’arawọn – Fálànà Ṣàlàyé Fún Buhari

YBTC Yorùbá—Gbajúgbajà amòfin tí ó tún jẹ́ ajá fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn nílẹ̀ wa, Amòfin Femi Fálànà ti sọ fún Ààrẹ Muhammadu Buhari ní ọjọ́ àìkú wípé àwọn ọmọ rẹ̀ kò lẹ́tọ̀ọ́ láti máa gun ọkọ bàálù ti ìjọba àpapọ̀ káàkiri. Fálànà tún bu ẹnu àtẹ lu lu bí agbẹnusọ fún Ààrẹ Muhammadu Buhari lórí […]

Categories
Ìròyìn

Èmi Kò Ní Kí Buhari Yan Ẹni Tí Yóò Gba Ipò Lọ́wọ́ Rẹ̀ Ní Ọdún 2023 – Bakare

YBTC Yoruba —Alaábòjútó Gbogbogbò ìjọ Citadel Global Community Church tí orúkọ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ rí ń jẹ́ Latter Rain Assembly, Olùsọ-Àgùntàn Tunde Bakare sọ ní ọjọ́ àìkú wípé òun kò sọ wípé kí Ààrẹ Muhammadu Buhari yan ẹni tí yóò gbà ipò lọ́wọ́ rẹ̀ ní ọdún 2023. Nínú ọ̀rọ̀ ránpẹ́ tí ó sọ nínú ìjọ rẹ̀, […]

Categories
Ìròyìn

Buhari Sọ̀kò Ọ̀rọ̀ Sí Fálànà, Ó Ní Kò Ní Àṣeyọrí Kan-an Pàtó

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari lánàá ọjọ́ ajé tí bu ẹnu àtẹ lu ògbóntàrigì a já fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn tí ó tú jẹ́ ọmọ Yorùbá, amòfin Femi Fálànà lórí ọ̀rọ̀ tí ó sọ lórí sáà kẹta. Buhari ṣàpèjúwe Falana wípé ẹni tí à ń pè ní a já fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn tí ó […]

Categories
Ìròyìn

Buhari Fi Ọwọ́ Agbára Yọ Olùṣàkóso Ìfìwéránṣẹ́, Ó Yan Alága Míràn Fún Ìgbìmọ̀ Ètò Ìbánisọ̀rọ̀

Bada Yusuf YBTC Yorùbá—Ààrẹ Muhammadu Buhari ní àná ọjọ́ ajé bu’wọ́ lu ìyọ́ni nípò Olùṣàkóso Ìfìwéránṣẹ́ (NIPOST) àgbà ilẹ̀ yìí, nígbà tí ó yan alága mìíràn sí ipò Aláṣẹ Ìgbìmọ̀ Ètò Ìbánisọ̀rọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ọ̀gbẹ́ni Bísí Adégbuyì ni Buhari yọ nípò nígbà tí Ọmọwé Ismail Adéwusì gbà’ṣẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀. Bákan náà, ó bu’wọ́ lu ìyanni […]