Categories
Ìròyìn

Tinúbú Ní Àwọn Ọ̀tá Tó Pọ̀ Gan Nínú APC – Onu

YBTC News YORÙBÁ— Àgbà ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Ọmọọba Onu ti sàlàyé wípé àwọn ọ̀tá Gómìnà Èkó tẹle rí, Asíwájú Bọ́lá Ahmed Tinúbú nínú ẹgbẹ́ APC ló ń ṣiṣẹ́ takòó. Onu sọ wípé àwọn ọ̀tá Tinúbú ọ̀ún ló ń gbé gbogbo àhesọ ọ̀rọ̀ wípé Tinúbú ati ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ń bá ara wọn jà […]

Categories
Ìròyìn

Tinúbú Ló Pegedé Jùlọ Láti Jẹ Ààrẹ Nàíjíríà – Doyin Okupe

YBTC News YORÙBÁ— Doyin Okupe, abẹ́sinkáwọ́ ààrẹ orilẹ èdè Nàìjíríà nígbà kan rì, Goodluck Ebele Jonathan ti fi èrò ọkàn rẹ̀ hàn nípa èròngbà Tinúbú fún ipò ààrẹ ọdún 2023. Okupe ní Asíwájú Tinúbú, ọ̀kan nínú àwọn àgbà ẹgbẹ́ APC, ní ẹni tí ò pegedé, tì ó sì kájú òṣùwọ̀n jùlọ nínú gbogbo àwọn tí […]

Categories
Ìròyìn

Ki APC Fa Ènìyàn Sílẹ̀ Lati Àríwá Fún Ipò Ààrẹ 2023 Túmọ́ Sí Sáà Kẹta Ni – Ndume

YBTC News YORÙBÁ— Adarí ilé Aṣòfin àgbà ní Abùjá nígbà kan rí, Sen. Ali Ndume, ti ẹgbẹ́ òṣèlú APC, ní ìhà gúsù Borno ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí àhesọ ọ̀rọ̀ ṣe ń lọ pé láti ìhà àríwá ni ọmọ oyè ààrẹ yóò ti wá. Ó ní tí ẹgbẹ́ òṣèlú APC bá leè fi irú […]