Categories
Eré Ìdárayà

Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Ti Orílẹ̀ Èdè Turkey Ti Sọ Burúkú Ọ̀rọ̀ Sí Ikọ̀ Tí ó Jáwe Gbéléẹ Lé Mikel Obi Lọ́wọ́

YBTC News Yorùbá-Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí fún ìgbìmọ̀ aláṣẹ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáwé gbéléẹ lé Mikel Obi lọ́wọ́ tí ó tún jẹ́ Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú orílẹ̀ èdè Turkey ìyẹn Ozkan Sumer ti sọ ọ̀rọ̀ burúkú sí Ikọ̀ Trabzonspor lórí bí Ikọ̀ náà ṣe ní kí Mikel Obi lọ rọ́kúnlé. Bákannáà ni Sumer sọ̀rọ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Mo Jábalé Ọmọ Ọdún Mẹ́rin Nítorí Wípé Ọ̀rẹ́ Ni Àwa Méjèèjì

YBTC News Yorùbá-Ọmọ ogún ọdún kan rèé ni ó ti kó sí akóló àwọn Ọlọ́pàá báyìí látàrí ẹ̀sùn ìjábalé ọmọ ọdún mẹ́rin kan, tí ó ní ọ̀rẹ́ òun ni. Arákùnrin náà tí ó pè ní Ọ̀gbẹ́ni Isaac Boniface ni ó ti jábalé ọmọ obìnrin ọmọ ọdún mẹ́rin ní àdúgbò Danwoh ní gúúsù Jos ní ìpínlẹ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Ìdí Rèé Tí A Kòle Ta Jálá Epo Kan Ní Márùn-únlèélọ́gọ́fà Owó Náírà – Àwọn Ọlọ́jà Epo Pẹtiró

YBTC News Yorùbá-Àwọn ọlọ́jà ilé epo pẹtiró nílẹ̀ yìí kò í tíì bẹ̀rẹ̀ sí ní ma ta jálá epo pẹtiró ní Márùn-únlèélọ́gọ́fà owó náírà tí Ìjọba àpapọ̀ pàṣẹ wípé tí wọ́n máà tá epo náà, ṣùgbọ́n àwọn ilé iṣẹ́ elépo tí Ìjọba nìkan ni ó ń tà á ní iye tí Ìjọba fọwọ́sí. Àwọn ilé […]

Categories
Ìròyìn

Àyẹ̀wọ̀ Fihàn Kedere Wípé Ọmọ Ilẹ̀ Ìtàló Tí ó Kó Coronavirus Wọ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà Kòní Àrùn Náà Lára Mọ́

YBTC News Yorùbá-Komíṣọ́nà fún ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn Ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Ayobami tí sọ pé ọmọ orílẹ̀ èdè Ìtàló tíó kó àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus wọ orílẹ̀ èdè yìí ni àyẹ̀wọ̀ ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé kò ní àrùn náà lára mọ́. Ó sọ eléyìí nìdí ìbánisọ̀rọ̀ tí ó bá àwọn oníròyìn ṣe ní […]

Categories
Ìròyìn

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Kéde Àwọn Ènìyàn Mẹ́rin Ti Titun Tí ó Ní Àrùn Coronavirus

YBTC News Yorùbá-Komíṣọ́nà fún ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn Ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Ayobami tí sọ pé àwọn ènìyàn mẹ́rin tuntun míràn ti ní àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus ní ìpínlẹ̀ Èkó báyìí. Ní ọjọ́ ọjọ́rú nígbà tí ó ń bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ lórí oun tuntun tí ó ti ń ṣẹlẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ àrùn kòkòrò corona, […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Sún Ayẹyẹ Gbogbo Eré Ìdárayá, ìyẹn National Sport Festival Síwájú Látàrí Àrùn Coronavirus

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti sún ayẹyẹ gbogbo eré ìdárayá tí ó ń má wáyé lọ́dọọdún ní orílè èdè yìí síwájú látàrí àtànkákẹ̀ àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus tí ó ń jà ràìnràín káàkiri àgbáyé lọ́wọ́ lọ́wọ́ yìí. Mínísítà fún eré ìdárayá ní orílẹ̀ èdè yìí, ìyẹn Sunday Dare kéde ọ̀rọ̀ yìí lẹ́yìn ìpàdé ránpẹ́ tí ó […]

Categories
Ìròyìn

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bayelsa Lọ Kí Buhari, Ó Ní Ààrẹ Gba Òun Bí Ọmọ Ni

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bayelsa tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ búra fún láìpẹ́ yìí, ìyẹn Ọ̀gbẹ́ni Diri Douye ṣe Baba kẹ́ẹpẹ́ sí Ààrẹ Muhammadu Buhari ní ọjọ́ ìṣẹ́gun, wọ́n sì ṣe ìpàdé pọ́ọ̀ ní olú ilé ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní Abuja, ìyẹn Aso Rock. Ìpàdé ránpẹ́ láàárín àwọn méjèèjì wá sí òpin ní ǹkan bi ago méjì […]

Categories
Ìròyìn

Oshiomhole Padà Sí Ẹnu Iṣẹ́ Gẹ́gẹ́ Bi Alága Gbogbogbò Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC, Ó Ní Òun Ṣetán Láti Ṣe Àgbéyẹ̀wò Ọ̀nà Òun no

Alága gbogbogbò ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), ìyẹn Comrade Adams Oshiomhole mú orin kòsógun mọ́, kòsọ́tẹ̀ mọ̀ọ́ bí ó ṣe padà sí ipò alága gbogbogbò ẹgbẹ́ òṣèlú náà. Ní ọjọ́ ìṣẹ́gun tí Oshiomhole darapọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ rẹẹ̀ nínú ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe ẹgbẹ́ òṣèlú náà, tí ó sì rọ gbogbo ìgbìmọ̀ náà wípé ọ̀rọ̀ orílẹ̀ […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ikọ̀ Chelsea Yóò Kábàámọ̀ Wípé Wọ́n Tàmí – Omeruo Sọ̀rọ̀

YBTC News Yorùbá-Agbábọ́ọ̀lù nípò ẹ̀hìn fún ikọ̀ Super Eagles, ìyẹn Kenneth Omeruo nírètí wípé Ikọ̀ Chelsea tí ó rà á yóò kábàámọ̀ wípé wọ́n tá òun sí Ikọ̀ Leganes ní orílẹ̀ èdè Spain. Ọdún 2012 ni Ikọ̀ Chelsea tọwọ́ agbábọ́ọ̀lú náà bọ̀wẹ́ àdéhùn ṣùgbọ́n tí kò kópa nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ kankan fún ikọ̀ náà rí. Láti […]

Categories
Ìròyìn

Láti Díje Dupò Ààrẹ Tàbí Gómìnà Ní Orílẹ̀ Èdè Yìí, O Gbọ́dọ̀ Ní HND – Ilé Aṣòfin Àgbà

YBTC News Yorùbá-Lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí, ó ti di ìgbà kejì tí ilé aṣòfin àgbà ti ka abádòfin tí ó ní wípé kí ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ díje du pò Ààrẹ àti ipò gómìnà ní orílẹ̀ èdè yìí gbọ́dọ̀ ní ìwé ẹ̀rí ti ilé ìwé gíga ti gbogbo nìṣe, ìyẹn HND tàbí èyí tí ó […]