Categories
Ìròyìn Uncategorized

Àjọ NLC Tí Gbé Ìfì Ẹ̀hónu Hàn Jákàjádò Nàíjíríà Dé Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nlá Abuja

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn àjọ tó ń rísí ọ̀rọ̀ òṣìṣẹ́ní orílẹ̀-ede Nàíjíríà, (NLC) ti gbé ìfi ẹ̀hónú han eyi tó jákèjádò Nàìjíríà lọ sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ńlá èyí tó kalẹ̀ sí Abùjá. Ìfi ẹ̀hónú hàn náà dálé lórí bí àwọn aṣòfin ti ń pinnu láti mú ìyípadà bá àbádòfin tó níí ṣe pẹ̀lú owó […]

Categories
Uncategorized

Àwọn Àlùfáà Ti Ìjọ Àgùdà Kọ Ìwé Àdúrà Láti Kọjú Àrùn Kòkòrò Coronavirus

YBTC News Yorùbá-Àwọn àlùfáà ti ìjọ Àgùdà, ìyẹn Bíṣọ̀ọ̀pù ìjọ Kátólíìkì ti ń kọmí inú lórí bí àrùn kòkòrò apanirun, ìyẹn Coronavirus ṣe gbòòrò si ní ilẹ̀ Áfíríkà àti káàkiri àgbáyé. Àwọn àlùfáà náà tí wọ́n sọ̀rọ̀ lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ kan tí wọ́n pè ní Symposium of Episcopa Conference of Africa and Madagascar kọ̀wẹ́ orin […]

Categories
Uncategorized

Ferdinand Yí Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ Padà Lórí Ighalo Bí Agbábọ́ọ̀lù Náà Ṣe Gbá Bọ́ọ́lù Mẹ́ta Sí Àwọ̀n

YBTC News Yorùbá-Ògbóntàrigì agbábọ́ọ̀lú tẹ́lẹ̀ rí fún ikọ̀ Manchester United, ìyẹn Rio Ferdinand ti ṣàlàyé ìdí tí òun ṣe yí ọ̀rọ̀ òun padà lóri bí Ikọ̀ Manchester United ṣe ti ọwọ́ Odion Ighalo bọ̀wẹ́ lórí àdéhùn mo yá ẹ ná fún ìgbà díẹ̀ nínú ọjà pàṣípàrọ̀ oṣù kìíní ọdún yìí. Ighalo tí ó gbá bọ́ọ́lù […]

Categories
Uncategorized

Buhari, Lawan àti Gbajabiamila Wọlé Ìpàdé Ìdakẹ́rọ́rọ́

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari ti wọ lé ipade pẹ̀lú àwọn olórí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin méjèèjì Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà, Ahmed Lawan àti Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin kékeré, Ọ̀gbẹ́ni Fẹ́mi Gbajabiamila ti wọlé ìpàdé Ìdakẹ́rọ́rọ́ tí ènìyàn kan kò lè ṣàlàyé ìdí ìpàdé náà. Ṣùgbọ́n Alamí fi tó àwọn oníròyìn létí wípé ìpàdé àwọn […]

Categories
Uncategorized

Alága Àjọ INEC Fẹsẹ̀fẹ Ní Ìpínlẹ̀ Imo Bí Àwọn Jàndùkú Ṣe Yabo Ìyàrá Ìkàbò

YBTC Yorùbá-Hílàhílo bẹ́ sílẹ̀ níbi tí Àjọ tí ó ń rí sí ètò ìdìbò ní orílẹ̀ èdè yìí, ìyẹn Independent National Electoral Commission, (INEC) tí ń ka àtúndì Ìbò aṣojú ṣòfin ti ìjọba ìbílẹ̀ Orlu/Orsu/Òru ti ìpínlẹ̀ Imo bí àwọn jàndùkú ṣe yabo Ìyàrá ìkàbò náà. Àwọn Jàndùkú náà na Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò tí ó wà […]

Categories
Uncategorized

Buhari Ò Bá Tinubu Ṣàdéhùn Wípé Òun Máa Gbéjọba Fun-un – Alága NIWA

YBTC Yorùbá- Akọ̀wẹ́ gbogbogbò tẹ́lẹ̀ rí ní ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) tí ó tún jẹ́ Alága ẹ̀ka tí ó ń rí sí ọ̀rọ̀ omi nílẹ̀ Nàìjíríà, ìyẹn Nigeria Inland Waterway Authority, George Muoghalu ti sọ wípé Ààrẹ Muhammadu Buhari kò bá Tinubu ṣe àdéhùn kankan lóri ọ̀rọ̀ Ààrẹ ní ọdún 2023. Muoghalu tí […]

Categories
Uncategorized

Eni Aluko Darapọ̀ Mọ́ Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Ikọ̀ Aston Villa

YBTC Yorùbá- Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú Aston Villa ti kéde ìyanni sípò Eni Aluko gẹ́gẹ́ bí Aláṣẹ àgbà fún bọ́ọ́lù àfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin. Bàbá Olówó Ikọ̀ náà, ìyẹn Christian Purslow sọ wípé Eni ti ṣiṣẹ́ takuntakun nínú Ikọ̀ náà gẹ́gẹ́bi agbábọ́ọ̀lú, ó ní inú Ikọ̀ náà ni Eni ti gbá ìfẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ àkọ́kọ́ rẹ̀, ó ní agbègbè […]

Categories
Uncategorized

Ashley Young Fi Orílẹ̀ Èdè Gẹ̀ẹ́sì Sílẹ̀, Ó Lọ Darapọ̀ Mọ́ Ikọ̀ Inter Milan Ní Orílẹ̀ Ìtàló

YBTC Yorùbá- Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú ti Inter Milan ní orílẹ̀ èdè Ìtàló lọ́ùń ti kéde ìfọwọ́bọ̀ ọmọ Ikọ̀ Manchester United, ìyẹn Ashley Young. Ọmọ ọdún Mẹ́rìlélọ́gbọ̀n naa darapọ̀ mọ́ Ikọ̀ Inter Milan pelu Mílíọ̀nù kan olè díè owó ilẹ̀ Aláwọ̀ funfun pẹ̀lú adehun ọlọ́dún kan. Inú ọdún 2011 ni agbábọ́ọ̀lú Young darapọ̀ mọ́ Ikọ̀ Manchester United […]

Categories
Uncategorized

Kò Sí Àpọ́nlé Kan Lára Ọba Tí Ó Ń Lọ Ilé-Ijó – Aláàfin Ọ̀yọ́ Sọ̀rọ̀

YBTC Yorùbá- Kò sí àpọ́nlé àti iyì kankan lára Ọba tàbí Olóyè Yorùbá tí ó ń lọ ilé ijó, mú ọtí tàbí fagbó kiri, Aláàfin Ikú Bàbá Yèyé ti Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Adeyeye ló sọ bẹ́ẹ̀. Ọba Adeyeye sọ̀rọ̀ yìí lánàá ní ìlú Ọ̀yọ́ níbi tí ó ti fi gbajúgbajà olórin fújì Yorùbá ìyẹn King […]

Categories
Uncategorized

Àwọn Ẹṣin-Ò-kọkú Ṣe Ìkọlù Ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Wọ́n Ta Àsíá Sókè

Àwọn ará àdúgbò Orin Èkìtì ní ìjọba ìbílẹ̀ Ìró-Òsì ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì ti figbeta bíi àwọn Ẹṣin-Ò-kọkú jàndùnkú ṣe ṣe ìkọlù ya wọ àwọn abúlé wọn. Àwọn ará àdúgbò náà ṣàlàyé síwájú si wípé àwọn Ẹṣin-Ò-kọkú náà ti ta Àsíá wọn sí òkè ní àwọn ààyè kàn-ǹ-kan ní àdúgbò wọn. Àti wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ oko wọn […]