Categories
Ìròyìn àgbáyé

Kàyééfì Ńlá: Ẹ Wo Ọmọ Tí Wọ́n Bí Pẹ̀lú Ǹkan Ọmọkùnrin Meta Papọ̀

YBTC News YORÙBÁ—  Ó jẹ́ ǹkan tó ya ènìyàn lénu. Àwọn dókítà gan pàápàá kò lè pa ẹnu dé pẹ̀lú bí wọn ṣe rí ọmọ tuntun ti wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ bí pẹ̀lú ǹkan ọmọkùnrin mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀. Gẹmẹ́gẹ́ bí ìwádìí ṣe sọ, àwọn dókítà náà sọ ọ́ gbangba gbàǹgbà pé ọmọ ọkùnrin náà ni ẹni àkọ́kọ́ tí […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Èèmọ̀! Ọmọ Ọdún Mẹ́tàlá Bímọ Lásìkò Ìdánwò Àṣejáde

YBTC News YORÙBÁ— Ọmọ ọdún mẹ́tàlá kan bímọ ní àsìkò tí wọn ń ṣe ìdánwò Ìsirò aṣejáde ìwé kẹfà tí ó ń lọ lọ́wọ́ ní agbègbè Mpigi ní orílẹ̀-èdè Uganda. Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹlẹ̀ ní ilé ìwé Alákọ́bẹ̀rẹ̀ St Balikuddembe, agbègbè Jalamba ní ìlú Buwama, Mpigi ní òwúrọ̀ òní Ọjọ́’rú, March 31. Gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá ilé ìwé, […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Buhari Yan Amokachi Gẹ́gẹ́bí Aṣojú Fún Bọ́ọ́lù Gbígbá Lórílẹ̀ Èdè Nàìjíríà

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari ti buwọ́lu agbábọ́ọ̀lú tẹ́lẹ̀ rí fún ilẹ̀ Nàìjíríà, tí ó tún ti gbá bọ́ọ́lù jẹun ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn Daniel Amokachi gẹ́gẹ́bi aṣojú bọ́ọ́lù gbígbá fún orílẹ̀ èdè yìí. Amokachi tí gbogbo wa mọ̀ sí “the Bull” ti gbá bọ́ọ́lù ní ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú àgbà orílẹ̀ èdè yìí, ìyẹn Super […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Dasuki Farahàn Fún Ìgbà Àkọ́kọ́ Láti Ìgbà Tí ó Ti Kúrò Làhamọ́n EFCC

YBTC Yorùbá- Olùbáni Dámọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ àbò fún Ààrẹ àná ìyẹn Sambo Dasuki farahàn nìléẹjọ́ fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ọjọ́ ọjọ́bọ, lẹ́yìn ọdún mẹ́rin tí ó ti wà ní àhamọ́ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè yìí. Dasuki ni ìjọba Ààrẹ Muhammadu Buhari fi sí àhamọ́ fún ọdún mẹ́rin pẹ̀lú bí oríṣiríṣi ilé ẹjọ́ ṣe gba onídùúró […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Ilẹ̀ Amẹ́ríkà Tí ń Gbèrò Báyìí Láti Gbégidínà Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Tí ó Ń Wọlé Amẹ́ríkà

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Donald Trump tí ń gbèrò báyìí láti fi àwọn ọmọ Nàìjíríà kún àwọn orílẹ̀ èdè tí Ìjọba ilẹ̀ ọ́ún ti fòte le láti máa wọn orílẹ̀ èdè náà bí ó ṣe wù wọ́n. Gẹ́gẹ́ bí Ìròyìn ṣe sọ, ilẹ̀ Amẹ́ríkà kòní fòte lée àwọn ọmọ Nàìjíríà pátápátá ṣùgbọ́n ó ma […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Ìgbéyàwó Ọmọmi Pẹ̀lú Ọmọ Adebutu Tó Forí Ṣọ́pọ́n Kòní Ǹkankan Ṣe Pẹ̀lú Ọ̀rẹ́ Èmi Àti Adebutu – Obasanjo

YBTC Yorùbá- Ààrẹ àná ní orílẹ̀ èdè yìí, Olóyè Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ ti sọ wípé ìgbéyàwó ọmọ òun, ìyẹn Olujuwon àti ti ọmọ gbajúgbajà Olówó tí ń fowó ṣàánú tí gbogbo wa mọ̀ sí Olóyè Kesington Adebutu tí ó jẹ́ ọmọbìnrin kò ní ǹkan ṣe pẹ̀lú ọ̀rẹ́ àwọn. Ọbásanjọ́ fèsì sì awuyewuye tí ó ń tí […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Àjọ JAMB Fòte Lé Gbígba Nọ́ḿbà Ìdánimọ̀ Kí Wọ́n Tó Lè Forúkọ Sílẹ̀ Fún Ìdánwò Àjọ Náà Ní Ọdún 2020

YBTC Yorùbá- Àjọ tí ó ń rí sí fíforúkọ sílẹ̀ fún ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga ní orílẹ̀ èdè yìí, ìyẹn Joint Admission and Matriculation Board (JAMB) ti fòte lé gbígba nọ́ḿbà ìdánimọ̀ ti ìjọba àpapọ̀ ìyẹn National Identification Number (NIM) kí àwọn ọmọ tó forúkọ sílẹ̀ fún ìdánwò náà. Oga agba Àjọ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Ilẹ̀ America Kò Báwo Sọ Ǹkankan Kí Ó Tó Ṣekúpa Olórí Jagunjagun Ilẹ̀ Iran – Saudi Fọhùn-ùn

YBTC Yorùbá- Orílẹ̀ èdè Saudi Arabia ti sọ̀rọ̀ lórí pípa Ìfináfọṣu tí orílẹ̀ èdè America pa olórí jagunjagun ilẹ̀ Iran. Saudi ní ilẹ̀ America kò fi ọ̀rọ̀ lọ òun kí ó tó gbé ìgbésẹ̀ náà. Saudi sọ ọ̀rọ̀ yìí lóri bí inúfu ẹ̀dọ̀fu ṣe ń wáyé wípé ilẹ̀ Iran yóò ṣe ìkọlù sí agbègbè rẹ̀. […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Trump Yín Ilẹ̀ Iran Léèkáná Bí Ikọ̀ Ológun America Ṣe Pa Olórí Jagunjagun Ilẹ̀ Náà Ní Ìpa Ìfináfọṣu

YBTC Yoruba—Ààrẹ Ilẹ̀ America, Ọ̀gbẹ́ni Donald Trump ní àárọ̀ ọjọ́ ẹtì ni ó fi ọ̀rọ̀ àkọ́kọ́ rẹ̀ sorí ẹ̀rọ alátagbà rẹ̀ láti ìgbà tí ikọ̀ bàálù agbérapá tí àwọn jagunjagun ilẹ̀ America ti ṣekú pa ọ̀kan gbòógì nínú àwọn jagunjagun ilẹ̀ Iran ní ọjọ́bọ ní ìlú náà. Trump nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ní orílẹ̀ èdè […]

Categories
Ìròyìn àgbáyé

Agbẹjọ́rò Àgbà Àti Mínísítà Ètò Ìdájọ́ Ilẹ̀ Yìí Tẹ́lẹ̀ Rí Yóò Ṣe Ọdún Kérésìmesì Ní Akóló Àwọn EFCC

YBTC Yorùbá –Àjọ tó ń rí sí ìṣe owó ìlú mákumàku nílẹ̀ wa, ìyẹn EFCC ti gba ìwé àṣẹ ní ilé ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ nílùú Abuja lánàá láti fi agbẹjọ́rò àgbà tí ó tún jẹ́ Mínísítà Ètò Ìdájọ́ Ilẹ̀ yìí tẹ́lẹ̀ rí Ọ̀gbẹ́ni Muhammed Bello Adoke sí Akóló rẹẹ̀ fún ọjọ́ mẹ́rìnlá gbáko. […]