Categories
Eré Ìdárayà

Real Madrid Dáná Sun Barcelona Bí Ẹran Iléyá,Ojú Messi Pọ́n

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn àgbààgbà ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Spanish Laliga, Real Madrid àti Barcelona jọọ wàákò ní pápá ìṣeré Santiago Bernabeu fun ijakadi tani yóò lékè tábìlì. Ẹ̀ẹ̀mejì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni Real Madrid to díyà jẹ Barcelona nínú ìdíje líìgì ni sáà yìí. Ní báyìí, Madrid ti bọ́ sí òkè téńté tábìlì, Atletico Madrid wà ní ipò […]

Categories
Eré Ìdárayà

Chelsea Pòkọ Ìyà Fún Crystal Palace, Liverpool Pa Aston Villa Lẹ́kún

YBTC News YORÙBÁ— Egbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Chelsea kanra mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn, Crystal Palace, wọ́n lù wọ́n bíi bẹ̀ǹbẹ́ nàbíyù pẹ̀lú àmì ayò mẹ́ẹ́rin sí ẹyọkan. Ami ayo meji kòǹgbà kòǹgbà ni Pulisic gbá wọlé kí Kurt Zouma àti Kai Havertz tóó gbá ayò kọ̀ọ̀kan wọlé. Liverpool bákan náà ẹ̀wẹ̀ fi àgbà hàn Aston Villa pẹ̀lú […]

Categories
Eré Ìdárayà

Leeds Utd Ká Man City Mọ́lé, Wọ́n Lù Wọ́n Bíi Bààrà

YBTC News YORÙBÁ—  Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Leeds United ti lọ bá Manchester City ní buba wọn, wọ́n lù wọ́n bíi bààrà lórí pápá ìṣeré wọn ní Etihad Ayò méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni agbábọ́ọ̀lù Leeds United Stuart Dallas gbá wọlé Manchester City, pẹ̀lú bí adarí ìdíje náà ṣe lé L.cooper kúrò ní orí pápá nígbà tí ó kù […]

Categories
Eré Ìdárayà

Manchester United Pòkọ Ìyà Fún Brighton, Newcastle Ba Ayọ̀Tottenham Jẹ́

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Manchester United ní alaye yìí wá láti ẹ̀yìn fi ìyà jẹ Brighton & Hove Albion. Ayò méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n gbá sínú àwọ̀n wọn. Bákan náà ẹ̀wẹ̀, ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Tottenham, èyí tí olùkọ́ni Jose Mourinho kó sòdí rí ìjákulẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn, Nígbà tí wọn sọ ìdíje náà di […]

Categories
Eré Ìdárayà

Chelsea Gba Àlejò Ọ̀ràn, Westbrom Ba Ọmọlúàbì Wọn Jẹ́.

YBTC News YORÙBÁ—  Awọn Yorùbá máa ń pòwe wípé a ò kìí sùn nílé ẹni kí á fi ọrùn rọ́. Òwe yìí kò ṣiṣẹ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Chelsea, wọ́n gbà àlejò ọ̀ràn nì ìrọ̀lẹ́ ònì ní pápá ìṣeré wọn, Stamford Bridge. Ayò máárù-ùn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni àwọn akẹgbẹ́ wọn, West Brom Albion, tì ó wá ká […]

Categories
Eré Ìdárayà

Super Eagles Gbomi Lójú Benin, Wọn Pegede Fún Ife Adúláwọ̀

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn gbajúgbajà agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Super Eagles tí lọ lu àwọn akẹgbẹ̀ wọn ní orílẹ̀ èdè Benin nínú kòmẹsẹ̀yọ ìfẹ́ ilẹ̀ adúláwọ̀. Ṣáájú ìdíje náà ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí pegedé fún Ife ilẹ̀ adúláwọ̀ nígbà tí àwọn akẹgbẹ́ wọn tó kù, Lesotho àti Sierra Leone gbá ọ̀mì ẹ lẹ́yìn. Super […]

Categories
Eré Ìdárayà

Man Utd Dáná Sun Westham, Juve Ju Cagilari Sí Kòtò

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Manchester United ní alẹ́ òní fi àgbà hàn akẹgbẹ́ wọn, Westham United ní pápá ìṣeré wọn, Old Trafford, èyí ni ìdíje tí ó kẹ́yìn lónìí. Ọ̀kan nínú agbábọ́ọ̀lù Manchester United, Mc Tominay ló kárí mọ́ bọ́ọ̀lù tó wá láti igun. Ṣùgbón lẹ́yìn àyẹ̀wò fínnifínni, wọ́n ní ọmọ ilé Westham náà […]

Categories
Eré Ìdárayà

Arsenal Yẹ̀yẹ́ Tottenham, Ojú Mourinho Pọ́n, Ó fẹ́ẹ́ ké

YBTC News YORÙBÁ— Ìdíje líìgì Gẹ̀ẹ́sì ń tẹ̀síwájú ni ìrọ̀lẹ́ òní ojọ́ Àìkú ní pápá ìṣeré ńlá ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Arsenal, Emirate. Láàrin Arsenal àti akẹgbẹ́ wọn Tottenham. Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Tottenham èyí tí olùkọ́ni Jisẹ Mourinho ló kọ́kọ́ rí àwọ̀n he, ní iṣẹju kẹrìnlálọ́gọ́ta láti ọwọ́ Eric Lamela, pẹ̀lú góòlù àràǹbarà tí ó gbá wọlé. Ṣùgbọ́n […]

Categories
Eré Ìdárayà

Everton Gba Àlejò Ọ̀ràn Nínú Ilé Wọn, Burnley Bọ̀ Wọ́n Bí Ẹja Tútù

YBTC News YORÙBÁ—Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Everton gba àlejò ọ̀ràn nínú pápá ìṣeré wọn, Goodison Park ní ìrọ̀lẹ́ òní, bí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Burnley ṣe ká wọn mọ́lé tí wọn sì nàwọ́n ní méjì sí ẹyọkan. Abala àkọ́kọ́, nígbà tí ìdíje náà wọ ìṣẹ́jú mẹ́tàlá ni Chris Wood gba ayò àkókó wọlé, tí McNeil sí fi èkejì lée […]

Categories
Eré Ìdárayà

Bayern Bayé Werder Bremen Jẹ́, Madrid Finá Má Elche

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Bayern Munich ṣe ẹgbẹ́ Werder Bremen ní ṣìbásìbo sí inú ilé wọn. Àmì ayò méta sí oókan ni wọ́n fi nàwọ́n. Bayern sì wà ní òkè téńté tábìlì líìgì Bundesliga. Atamétàsé wọn, Robert Lewandowski sì tún fi ìwé ìtàn titun balẹ̀ pẹ̀lú ayò tó gbá wọ inú àwọ̀n Bremen. Ó […]