Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Ya wọ Agbègbè Benue, Ọ̀pọ̀ Ẹ̀mí Ló Sòfò

YBTC News YORÙBÁ—Àwọn Agbébọn kan, ni ọjọ Ìṣẹ́gun ni a gbọ́ pé wọ́n ya wọ agbègbè Benue, Tordonga, ní ìhà ìjọba ìbílẹ̀ Katsina-Ala. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀mí ló sòfò tí ọ̀pọ̀ sì fara pa yánnayànna. Ìpayà ti bo gbogbo àgbègbè náà kan léyí tí ó fa àìlè roko àìlè rodò àwọn àgbẹ àti ìdẹnukọlẹ̀ gbogbo ọrọ̀ ajé […]

Categories
Ìròyìn

Wàhálà Bẹ́ silẹ̀ Ní Òǹdó Láàrin Àwọn Ẹgbẹ́ Awakọ̀ NURTW, Ẹ́mí Kan Ti Bọ́!

YBTC News YORÙBÁ— Ọ̀rọ̀ tí di bóò-lọ-o-yà fún mi ní òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ìsẹ́gun láàrin àwọn ẹgbẹ́ awakọ̀ ní, olú ìlú Òǹdó. A ríi gbọ́ wípé ara àwọn ọmọlẹ́yìn àti alátẹ̀lé alága ẹgbẹ́ awakọ̀ (NURTW) Jacob Adébọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ìdájọ́ dìgbò lu àwọn ẹgbẹ́ Kejì wọn. Nígbà tí ìjà náà bẹ́ sílẹ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Ìjà Ẹ̀sìn: Ìjọba Kwara Ti Rán Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Sí Àwọn Ilé Ìwé Tí Wọ́n Tìpa

YBTC News YORÙBÁ—Inú fu- àyà fu àti ìbẹ̀rù ti bo ìlú Ìlọrin, olú ìlú Kwara kan láti ìgbà tí ìjọba ìpínlẹ̀ náà ti pàṣẹ pé kí wọn ti àwọn ilé ìwé ìhìnrere ẹlẹ́sìn kristẹ̀nì pa. A ríi gbọ́ wípé àwọn ilé ìwé náà tako ìlo hijab (ìborí mùsùlùmí) láàrin àwọn ọmọ ilé ìwé tó jẹ́ […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn ohun ìjà tí àwọn Fúlàní daran-daran kó ti tẹ Àmọ̀tẹ́kùn Ìlú Ìbàdàn lọ́wọ́

Àwọn ohun ìjà tí àwọn Fúlàní daran-daran kó ti tẹ Àmọ̀tẹ́kùn Ìlú Ìbàdàn lọ́wọ́ Àwọn òṣìṣẹ́ Ààbò tí Ìpínlè Òyó tí a mọ̀ síi Amọtẹkun ti gbẹ́sẹ̀lé ọkọ̀ nlá kan ti o kosinu àwọn ọkùnrin tí wọn kò tó ọgọ́rin tí wón fura sí pé àwọn darandaran Fulani ni agbègbè Iwo Road ti Ìbàdàn, olu […]

Categories
Ẹjọ́ wẹ́wẹ́ Ìròyìn

YBTC Yorùbá bá Fáyẹmí yọ̀ bí ó ṣe pé ọdún mẹ́rìn dín lọ́gọ́ta láyé

YBTC Yorùbá bá Fáyẹmí yọ̀ bí ó ṣe pé ọdún mẹ́rìn dín lọ́gọ́ta láyé A ba Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkìtì Josua Fáyẹmí yọ̀ fún ọjọ́ ìbí òní, igba ọdún ọdún kan, a ṣe ní ádùrá wípé kí bàtà ó pẹ́ lẹ́sẹ̀ àti wí pé kí o máa ṣe dáadáa síwájú síi. Dáadáa tí ó fí bẹ̀rẹ̀ […]

Categories
Ìròyìn

“Mọ̀ Nípa Ọ̀gágun Zubairu Tí Buhari Ṣẹ̀ṣẹ̀yàn”

(Chief of Navy staff)Oṣù Kẹrin Ọjọ́ Kejì le lógún, Ọdun 1966 ni wọn bí Ọ̀gágun Awwal Zabairu Gambia. Ìpínlè Kano ni wọn bíi si láti Ìjọba Ìbílè Nassarawa ti Ìpínlè Kano, o sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti Déédé Course 36 ti Ilé-ìwé gíga ààbò Nàìjíríà. Ó forukọ sílẹ̀ sí Ọgagun Nàìjíríà ní ọjọ́ kẹrin le […]

Categories
Ìròyìn

“Mọ̀ Nípa Ọ̀gágun Lucky Tí Buhari Ṣẹ̀ṣẹ̀yàn”

(Chief of Defence Staff)Wọ́n bí Maj. Gen. Lucky Eluonye Onyenuchea Irabor ní 5 Oṣu Kẹwa ọdún 1965 ní Aliokpu Agbor, ní ìjọba ìbílẹ̀ Ika South Local Government Area ti Ipinle Delta, Nigeria. Wọn lọsí Ile-ẹkọ giga ti Idaabobo Naijiria (NDA) Kaduna gẹgẹbi ọmọ ẹgbẹ ti 34 Regular Course ni 1983 ati pe o gba Igbimọ […]

Categories
Ìròyìn

“Mọ̀ Nípa Ọ̀gágun Attahiru Tí Buhari Ṣẹ̀ṣẹ̀yàn”(Chief of Army Staff)

“Mọ̀ Nípa Ọ̀gágun Attahiru Tí Buhari Ṣẹ̀ṣẹ̀yàn”(Chief of Army Staff) Ọ̀gá jagunjagun orí ilẹ̀: Ọmọ abínibí Ìpínlè Kaduna ni Mr Attahiru, won bíi ní Oṣù Kẹjọ Ọjọ́ kẹwàá, Ọdún 1966. Titi di ipinnu ipade rẹ laipẹ, oun ni Oṣiṣẹ Gbogbogbo ti n paṣẹ Pipin 82 ti Ẹgbẹ ọmọ-ogun Naijiria, Enugu. Pẹ̀lú nọmba iṣẹ́ 8406, ó […]

Categories
Ìròyìn

“Mọ̀ nípa Ọgágun Amao tí Buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ Yàn”(Chief of Air Staff)

“Mọ̀ nípa Ọgágun Amao tí Buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ Yàn”(Chief of Air Staff)-YBTC NEWS YORÙBÁ Air Marshal Isiaka Oladayo Amao, wọ́n bí i ní ojó kẹrinla Oṣù Kẹsàn-án 1965, bíbí àti dàgbà ní Ìpínlè Enugu Gúúsù ìlà oòrùn Nigeria.Lẹ́yìn náà ó lọ sí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun pẹ̀lú àwọn òbí rẹ̀ kì wón tún tó lọ sí ìpínlẹ̀ Kaduna […]