Categories
Ìròyìn

Àwọn Àgárá Ọlọ́sà Ti Fọ́ Ilé Ìfowópamọ́ Kan Ní Ọ̀sun

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn àgárá ọlọ́sà, alọ-kólóhunkígbe kan ti dìgbò lu ilé ìfowópamọ́ New Generation Bank  ní ìlú Òkukù ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun. Inú fu àyà fu, ìbẹrù àti ojo ló ti bo gbogbo àwọn ará ìlú Òkukù tí ó wà ní ìjọba ìbílẹ̀ Odõ-Ọ̀tìn ni ìpínlẹ̀ náà, pẹlú bí àwọn ilé Agbébọn se fọ́ ilé […]

Categories
Ìròyìn

Ìgbẹ́jọ́ Maina: Fálànà Yawọ Ilé Ẹjọ́, Ó Ní Òun Ṣetán Láti Jẹ́rìí

YBTC News YORÙBÁ—  Agbẹjọ́rò àgbà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Fẹ́mi Fálànà ní òní ọjọ́bọ̀ ti fa ara rẹ̀ sílẹ̀ láti lọ jẹrìí AbdRasheed Maina, tí ó ń jẹ́jọ́ lọ́wọ́. Maina ni àwọn àjọ tí ó ń rísí ìlú owó ará ìlú ní póńpó ka onírúurú ẹ̀sùn méjìlá sí lọ́rùn nípa bí ó ṣe ṣe owó […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Afurasí Agbébọn Ti Jí Àwọn Ọmọ Akẹ́kọ̀ọ́ Àti Olùkọ́ Gbé Ní Ẹdo

YBTC News YORÙBÁ— Ilé iṣẹ́ apàṣẹ ọlọ́pàá tí ìpínlẹ̀ Edo ti jẹ́rí sí bí àwọn afurasí Agbébọn kan ṣe yawọ ilé ẹ́kọ́ Ìmọ̀-ẹ̀rọ Ìkọ́lé kan ní ìpínlẹ̀ Edo, ti wọ́ sì jí àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ sálọ. Ilé ẹ̀kọ́ yìí ni ó wà ní ìlú Uromi, ni ìjọba ìbílẹ̀ àríwá- ìyọ oòrùn Esan ni […]

Categories
Ìròyìn

Fálànà Bu Ẹnu Àtẹ́ Lù Ìjọba Àpapọ̀, Ó Ní Delta Ni Owó Ibori Tọ́ Sí

YBTC News YORÙBÁ—  Agbẹjọ́rò fún ìjà fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn tó gbajúgbajà nnì, Fẹ́mi Fálànà ti kòrò ojú sí ìjoba àpapọ ṣe gbé ẹsẹ̀ lé owó tí wọn gbà lọ́wọ́ James Ibori. Ó ní ìpínlẹ̀ rẹ̀ ló nií, kìí ṣe ìjọba àpapọ̀. Ó bu ẹnu àtẹ́ lu bí wọ́n ṣe ya owó náà sọ́tọ̀ láti […]

Categories
Ìròyìn

Ìfi Ẹ̀hónúhan: Ọ̀yọ́, Sokoto, Rivers, Àbújá, Èkìtì, Kwara Àti Àwọn Ìpínlẹ̀ Ìyókù Kópa Nínú Ìfi Ẹ̀hónúhàn Jákèjádò Nàíjíríà

YBTC News YORÙBÁ— Ìfi ẹ̀hónúhàn láàrín àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ tí ó ń rí sí ìgbàáyé gbádùn àwọn òṣìṣẹ́, NLC, ló ti gba gbogbo orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kan láti àfẹ̀mọ́jú òní. Jákàjádò Nàíjíríà ni gbogbo àwọn ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ti jáde láti ṣe ìfi ẹ̀hónú hàn fún bí àwọn ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ńlá Abuja ṣe ń ṣe ìfáárà […]

Categories
Ìròyìn

Ìdí Nìyí Tí A Ó Fi Níí Dá Owó Ti A Gbà Lọ́wọ́ Ibori Padà Sí Àpò Delta- Malami

YBTC News YORÙBÁ—  Amòfin àgbà gbogbogbò fun ètò ìdájọ́ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí sàlàyé lẹ́kúnrẹ́rẹ́ ìdí tí àwọn kò ṣe níí dá owó tí àwọn gbà lọ́wọ́ James Ibori Padà sí kòtò asuwon ìpínlẹ Delta. Malami tẹ̀síwájú nínú àlàyé rè wípé àwọn yóò lo owó náà láti fi ṣe àkànṣe iṣẹ ìjọba àpapọ̀ ni. Bí […]

Categories
Ìròyìn

Àjáàbalẹ̀: AGF Abubakar Malami Ti Káṣọ Lójú Eégún Lórí Ọ̀rọ̀ Ìṣèwádí Owó Lọ́dọ̀ Asíwájú Tinúbú

YBTC News YORÙBÁ— Amòfin gbogbogbò nnì tí ó tún jẹ́ mínísítà fún ètò ìdájọ́ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Abubakar Malami (SAN), ti ṣe àlàyé lẹ́kúnrẹ́rẹ́ lórí àhesọ ọ̀rọ̀ wípé ọ́fíìsí òhun ń ṣe ìwádí Asíwájú Tinúbú. Bí a ò bá gbàgbé, a ó rántí ọ̀rọ̀ àhesọ kan tó ń jà ràinràin láìpé yìí wípé wọn ń ṣe […]

Categories
Ìròyìn Uncategorized

Àjọ NLC Tí Gbé Ìfì Ẹ̀hónu Hàn Jákàjádò Nàíjíríà Dé Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nlá Abuja

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn àjọ tó ń rísí ọ̀rọ̀ òṣìṣẹ́ní orílẹ̀-ede Nàíjíríà, (NLC) ti gbé ìfi ẹ̀hónú han eyi tó jákèjádò Nàìjíríà lọ sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ńlá èyí tó kalẹ̀ sí Abùjá. Ìfi ẹ̀hónú hàn náà dálé lórí bí àwọn aṣòfin ti ń pinnu láti mú ìyípadà bá àbádòfin tó níí ṣe pẹ̀lú owó […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ààrẹ Buhari Ti Yan Ahmad Halilu Gẹ́gẹ́ Bí Olùdarí Àgbà fún NASRDA

YBTC News YORÙBÁ— Ààrẹ Buhari ti fi orúkọ arákùnrin Ahmad Halilu ráńsẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdarí àgbà Titun fún ilé iṣẹ́ tí ó ń rísí ìsèwádí ojú afẹ́fẹ́ sí àwọn ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà tó kalẹ̀ sí Abùjá. Gẹ́gẹ́ bí agbẹnusọ ààrẹ, Garba shehu se sọ, nígbà tí ó n bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀. Ó sọ […]

Categories
Ìròyìn

Ààbò Ẹ̀sọ́ Ogun Naijiria Pa Àwọn Eesin-ò- kọkú Boko Haram Run, Wo Òǹkà Àwọn Tí Ó Kú

YBTC News YORÙBÁ— Àgbájọ àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Nàìjíríà tí dìgbò lu àwọn eesin- ò- kọkú Boko Haram tí kò dín ni mẹ́talélọ́gbọ̀n ni Chikingudu, wọ́n sì pa gbogbo wọn run ní gàá wọn. Chikingudu jẹ́ ìletò kan ní ìjọba ìbílẹ̀ Marte ní ìpínlẹ̀ Borno. Abule Missene, Hausari ati Chikungudu   ní àwọn ọmọ ogun […]