Categories
Eré Ìdárayà

Jamaal Ba Ayọ̀ Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Aston Villa Jẹ́, Ó Gbà Bọ́ọ̀lù Sínú Àwọ̀n Wọn Ní Àkókò Ìdádúró

YBTC News YORÙBÁ—Ní alẹ́ àná, ní ìgbà tí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Newcastle United ń wàá kò olú àwọn akẹgbẹ́ wọn, Aston Villa ní pápá ìṣeré St James’ Park. Ọ̀mì ayò kọ̀ọ̀kan ní ìdíje náà parí sí. Ìdíje náà yọ eruku lálá láti ìbẹ̀rẹ̀, nígbà tí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù kankan kò rí ayò gbá wọlé. Ṣùgbọ́n nígbà tí […]

Categories
Ìròyìn

Àjọ NYSC Ti Fi Ọwọ́ Òṣì Júwe Ilé Fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n Lórí Ìwà Àìtọ́

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn olùsàkóso àjọ tí ń rísí ètò àgùnbánirọ̀ àwọn ọdọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàíjíríà ti fi ọwọ́ òṣì júwe ilé fún àwọn òṣìṣẹ́ wọn mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n fún oríṣìíríṣìí ìwà àìtọ́. Olùdarí àgbà fún àjọ náà, Ibrahim Shuaib fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àwọn gbé ìgbésẹ yìí láti kó àwọn òṣìṣẹ́ àwọn ní ìjánu àti láti […]

Categories
Ìròyìn

Ìjàǹbá Ọkọ̀ Ti Gba Ẹ̀mí Èníyàn Mọ́kàdínlọ́gbọ̀n, Àwọn 188 Ṣí Fara Pa Yánnayànna Ní Ọ̀ṣun

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn àjọ tó ń rí sí lílọ bíbọ̀ ìrìnà ojú pópó FRSC, ní Ọ̀ṣun tí ṣe àgbéjáde òǹkà àwọn tí ó bá ìṣẹ̀lẹ̀ jàǹbà ọkọ̀ lọ ní Ọ̀ṣun láàrín oṣù kínní sí oṣù Kejì ọdún yìí. Wọ́n ṣàlàyé pé ènìyàn mọ́kàndílọ́gbọ̀n ló ti gbé ẹ̀mí mì níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà, tí àwọn mẹ́jọlélọ́gọ́sàn-án […]

Categories
Ìròyìn

Arákùnrin Kan Ní Òǹdó Ti Fipá Bá Ọmọdébìnrin Kan Sùn Lọ Sí Ọ̀run Ọ̀sán Gangan

YBTC News YORÙBÁ— Ọmọdébìnrin kan, Esther Friday tí kò ju ọdún mẹ́wàá lọ ni arákùnrin àgbẹ̀ kan, Israel Ikúmúyì, ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́- gbọ̀n ti fi ipá bá sùn títí tó fi gbẹ́mí mì. Ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú náà sẹlẹ̀ ní ìlú Igbótako ní ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ní ìpínlẹ̀ Òǹdó. Arákùnrin náà tan ọdọmọbìnrin naa wọlé pé òun […]

Categories
Ìròyìn

Ìjọba Kaduna Ti Kéde Àwárí Àwọn Ọmọ Ilé Ìwé Ọgọ́sánTí Wọ́n Jígbé

YBTC News YORÙBÁ—  Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kaduna ti kéde pé àwọn ọmọ ilé-ìwé ọgọ́sán nínú àwọn tí wọ́n jígbé ni àwọn ọmọ ogun ti ṣe àwárí wọn. Ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ yìí ni àwọn ọmọ ilé ìwé ìjọba kan, Federal College of Forestry Mechanization, Afaka, ní ìjọba ìbílẹ̀ Igabi ní ìpínlẹ̀ Kaduna. Ẹ rántí pé ní òru […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Ajọ́mọgbé Ti Gbé Àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin Ọmọ Ilé-Ìwé Ní Kaduna

YBTC News YORÙBÁ— Agbẹnusọ ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ Kaduna, ASP Mohammed Jalige ti jẹ́rì síi wipe lóòótọ ni àwọn Ajọ́mọgbé gbé àwọn ọmọ ilé-ìwé, ṣùgbọ́n àwọn ò tíì mọ pàtó iye ọmọ tí wọn kó lọ. Jalige tẹ̀síwájú pé ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá tí ń ṣiṣẹ́ takuntakun pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ilé iṣẹ́ ológun láti dóòlà àwọn […]

Categories
Ìròyìn

Àjọ NNPC Tako PPPRA, Wọ́n Dá Owó Epo Pẹtiróòlù Padà Sí Bó Ṣe Wà Tẹ́lẹ̀

Àwọn àjọ tó ń rísí ọ̀rọ̀ epo Pẹtiróòlù ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NNPC ti gbójú agan wo bí ìròyìn ṣẹ gba gbogbo ìlú àti àtẹ ayárabíàsá wípé ẹ̀kúnwó ti bá owó epo. Wọ̀n sì takú lórí ọ̀rọ̀ wọn pé kò sí àlékún kankan tó bá owó epo ní oṣù kẹta yìí. Eléyìí tako ìwé owó titun […]

Categories
Ìròyìn

Epo Pẹtiróòlù Ti Gbówó Lórí Gọbọi! N212 Ni Lítà Kan Báyìí

YBTC News YORÙBÁ— Kò ì tíì ju ọjọ́ mọ́kànlá báyìí tí àwọn ilé iṣẹ́ tó ń ṣe ètò bí epo Pẹtiróòlù ṣe ń jáde bọ́ sọ́dọ̀ ará ìlú ṣe ìlérí fún gbogbo ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wípé àwọn kò níí fí owó kún owó epo náà. Ní báyìí, epo ti gbówó lórí, wọ́n sì ti sọọ́ […]

Categories
Ìròyìn

Àgùnbánirọ̀ Àti Ọmọ Àkẹ́kọ̀ọ́ Kan Ti Jí N9m Ni Apo Yunifasiti

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn àjọ tó ń rísí bí wọ́n ṣe n̄ ṣe owó ìlú kúmakùma ló ti fi páńpẹ́ òfin mú àgùnbánirọ̀ kan, Nazim Usman Gomna, àti ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásitì AlHikmah onípele kẹrin Idris Shuaibu Suleiman. Àwọn arákùnrin méjì yíì, níwájú ilé ẹjọ́ ńlá ìlú Ìlọrin, ni wọ́n ká ẹ̀sùn sí lọ́rùn gẹ́gẹ́ bí […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Àgbẹ̀ Àti Fúlàní Darandaran Fẹnu kò Pọ̀ Láti Gba Ọgbà Ẹran Láàyé Ní Èkìtì

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn àgbẹ̀ àti àwọn Fúlàní darandaran lóní ọjọ́’bọ̀, ni Ekiti ti fẹnu kò pọ̀ jókòó àlàáfíà láti gba ọgbà ẹran láàyè ní ìpínlẹ̀ náà láti mú òpin bá gbọn mí sii- omi ò tóo ní ìpínlẹ̀ naa. Alága ìpínlẹ̀ náà fún gbogbo ẹgbẹ àwọn àgbẹ, Arákùnrin Enoch Alágbádá àti alága ẹgbẹ́ àwọn […]