Categories
Ìròyìn

Ṣàdédé N’iná Ṣẹ́yọ Ní Pápá Òfurufú Owerri, Ní Ìpínlẹ̀ Imo

YBTC Yorùbá- Iná Àgbamú ramúramù ni ó ti ṣẹ́yọ ni pápá ọkọ̀ òfurufú ti Owerri tí a mọ̀ sí Ṣàn Mbakwe International Cargo Airport, Owerri. Ìdí ìṣẹ̀lẹ̀ iná náà kò í tíì yé ẹnikẹ́ni ṣùgbọ́n ọgbà agb ẹ̀ka tí ó ń rí ìgbòkègbòdò ọkọ ofurufu ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ìyẹn Federal Airport Authority, Mrs. Henrietta […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Lórí Owó Òṣìṣẹ́ Tó Kéré Jùlọ: Àjọ Ẹgbẹ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Lápapọ̀ Yóò Dásí Ìkùnsínú Tówà Láàrin Wike àti Ẹgbẹ́ Òṣèlú Ní Ìpínlẹ̀ Rivers

YBTC Yorùbá- Òye tí ń fojú hàn báyìí wípé ìkùnsínú tó wà láàárín ìjọba ìpínlẹ̀ Rivers àti àjọ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ìyẹn Nigerian Labour Congress (NLC) ẹ̀ka ti ìpínlẹ̀ Rivers yóò wà sí òpin láìpẹ́ bí àwọn olórí òṣìṣẹ́ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ṣe ń gbìyànjú báyìí láti dá sí ááwọ̀ náà. Ṣáájú àsìkò yìí ni àjọ […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Ọlọ́pàá Gba Ọmọbìnrin Ọdún Mẹ́rìnlá Sílẹ̀ Lọ́wọ́ Àwọn Ajínigbẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Anambra

YBTC Yorùbá- Àwọn Ọlọ́pàá ní olú ìlú ìpínlẹ̀ Anambra, ìyẹn ní Onitsha ti gba ọmọbìnrin ọmọ ọdún mẹ́rìnlá kan sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ajínigbé tí wọ́n jí ọmọbìnrin náà gbé ní ǹkan bi oṣù kan sẹ́yìn. Agbẹnusọ fún àwọn Ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ náà, ìyẹn Haruna Muhammed ní ọjọ́ ajé sọ fún àwọn oníròyìn wípé àwọn ti […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Gómìnà Ìwọ̀ Oòrùn Gúúsù Ilẹ̀ Nàìjíríà Ń Gbèrò Láti Kọ̀wẹ́ Sí Ọ̀gá Àgbà Ọlọ́pàá Ilẹ̀ Yìí Lóri Bí Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn Yóò Ṣe Ma Lo Ìbọn

YBTC Yorùbá- Òye tí ń fojú hàn báyìí wípé àwọn ilé Aṣòfin ìpínlẹ̀ ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ yìí yóò jókòó ṣe àgbéyẹ̀wò òfin ìdásílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn ní ìpínlẹ̀ kóowa wọn ní ọjọ́ ọjọ́ ọjọ́rú. A tún gbọ́ wípé àwọn Aṣòfin náà yóò ṣe àgbékalẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò míì tí yóò ma ṣe àbójútó Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn ní […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ìdí Rèé Tí Mofi Yọ Ẹni Tí ó Jẹ́rí Takòmí Lórí Bí Ilé Aṣòfin Àgbà Ṣe Fẹ́ Yọmí Nípò Ààrẹ – Donald Trump

YBTC Yorùbá- Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, ìyẹn Ààrẹ Donald Trump ti ṣàlàyé lọ́jọ́ àbàmẹ́ta ìdí tí ó fi jáwe gbélé ẹ lé olórí jagunjagun kan tí ó jẹ́ ẹ̀rí takò ní ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin nígbà ìjíròrò lóri bóyá kí wọ́n yọ́ nípò tàbí kí wọ́n má yọ̀ọ́. Ní ọjọ́ ẹtì ni wọ́n sin Ọ̀gágun Alexander Vindman […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ìfẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ Kejìlélógún Rèé Tí Ahmed Musa Tigbá Bọ́ọ́lù Sáwọ̀n Gbẹ̀yìn

YBTC Yorùbá- Balógun Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú Super Eagles, Ahmed Musa tí ó ń tún gbá bọ́ọ́lù jẹun ní ikọ̀ Al Nassr ní orílẹ̀ èdè Saudi Arabia ti kùnà láti tún gbá bọ́ọ́lù sáwọ̀n fún ikọ̀ rẹ̀ nínú ìdíje àgbákuta líígì ilẹ̀ Saudi. Nínú ìfẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ tí Ikọ̀ rẹ̀ ti kojú Ikọ̀ Al Fateh FC ni wọ́n gbá […]

Categories
Eré Ìdárayà

Alex Iwobi Nírètí Wípé Òun Yóò Ma Gbá Bọ́ọ́lù Déédéé Lábẹ́ Carlo Ancelotti

YBTC Yoruba—Agbábọ́ọ̀lù ọmọ Nàìjíríà ní ipò àárín, tí ó tún gbá bọ́ọ́lù jẹun ní ikọ̀ Everton ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì ni ó ti ní ìrètí báyìí wípé òun yóò ma gbá bọ́ọ́lù déédéé lábẹ́ Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá tuntun fún ikọ̀ ọ̀ún, ìyẹn Carlo Ancelotti. Iwobi tí ó kópa nínú ìfẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ mẹ́fà tí Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Carlo Ancelotti ti kópa […]

Categories
Eré Ìdárayà

Barcelona, Real Madrid Tí ń Gbìyànjú Láti Tọwọ́ Osimhen Bọ̀wé

YBTC Yorùbá-Òye tí ń fojú hàn báyìí wípé àwọn Orogún méjèèjì nínú ìdíje líígì ilẹ̀ Spain, ìyẹn Ikọ̀ Barcelona àti Ikọ̀ Real Madrid tí ń jà fitafita láti tọwọ́ agbábọ́ọ̀lú Ikọ̀ Lille, Victor Osimhen bọ̀wẹ́ bí sáà igbá bọ́ọ́lù míì ṣé ń fojú hàn. Ikọ̀ méjèèjì ni wọ́n tí ń gbìyànjú láti ṣà lékún agbára […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣòfin Ilẹ̀ Nàìjíríà Kọ Àbá Kíkó Ọmọ Nàìjíríà Kúrò Ní Orílẹ̀ Èdè China Nítorí Àrùn Coronavirus

YBTC Yorùbá- Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ṣòfin ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọjọ́ ìṣẹ́gun ti kọ ìpè tí àwọn kan ń pè wípé kí ìjọba ilẹ̀ yìí kó àwọn ọmọ Nàìjíríà kúrò ní orílẹ̀ èdè China nítorí àrùn Coronavirus tí ó gbalẹ̀ kan ní orílẹ̀ èdè ọ̀ún. Alága fún ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin náà lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn àti ìkéde, […]

Categories
Ìròyìn

Lógún-Lọ́gbọ̀n Ènìyàn Há Sínú Súnkẹrẹ Fàkẹrẹ Ọkọ̀, Ọ̀gọ̀ọrọ̀ Nfẹsẹ̀ Rìn Bí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Ṣe Fòfin De Ọ̀kadà àti Márúwá

YBTC Yorùbá- Pẹ̀lú bí ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ṣe fòfin de Ọ̀kadà alùpùpù àti kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́ta ní àwọn ojú pópó ti ìpínlẹ̀ Èkó kan, súnkẹrẹ fàkẹrẹ kò tìtorí rẹ dínkù ní àwọn òpópónà ìpínlẹ̀ Èkó. Kódà ọ̀gọ̀ọrọ̀ ènìyàn ni wọ́n ní fẹsẹ̀ wọn rin ọ̀pọ̀lọpọ̀ máìlì. Oníròyìn tí ó ń lọ káàkiri àwọn òpópónà ti […]