Categories
Ìròyìn Uncategorized

Àjọ NLC Tí Gbé Ìfì Ẹ̀hónu Hàn Jákàjádò Nàíjíríà Dé Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nlá Abuja

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn àjọ tó ń rísí ọ̀rọ̀ òṣìṣẹ́ní orílẹ̀-ede Nàíjíríà, (NLC) ti gbé ìfi ẹ̀hónú han eyi tó jákèjádò Nàìjíríà lọ sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ńlá èyí tó kalẹ̀ sí Abùjá.

Ìfi ẹ̀hónú hàn náà dálé lórí bí àwọn aṣòfin ti ń pinnu láti mú ìyípadà bá àbádòfin tó níí ṣe pẹ̀lú owó òṣìṣẹ́ tó kéré jùlọ.

Ìròyìn fi tówa létí pé ìfí ẹ̀hónú yìí káàkiri gbogbo ipinlẹ tó wà ní orílẹ̀ èdè yìí. Àbádòfin yìí ni asòfin Garba Mohammed  lati ìhà ẹkùn Sabo Gari ni Kaduna ṣe agbátẹrù rẹ̀.

Bí wọn bá bú ọwọ́ lu àbádòfin yìí, yóò mú àdínkù bá ẹgbẹ̀run lọ́nà ọgbọ̀n Naira ti ìjọba àpapọ̀ ti buwolu lù to gẹ́gẹ́ bíi owo òṣiṣẹ́ tó kéré jù tàbí kí wọ́n ti má kọbi ara síi mọ́.

Nínú àwọn tó ń fi hàn yìí lati rí onírúurú àwọn tí ó gbé pátákó tí wọn kọ orísìí rídìí nǹkan sí