Categories
Ẹjọ́ wẹ́wẹ́ Ìròyìn

YBTC Yorùbá bá Fáyẹmí yọ̀ bí ó ṣe pé ọdún mẹ́rìn dín lọ́gọ́ta láyé

YBTC Yorùbá bá Fáyẹmí yọ̀ bí ó ṣe pé ọdún mẹ́rìn dín lọ́gọ́ta láyé

A ba Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkìtì Josua Fáyẹmí yọ̀ fún ọjọ́ ìbí òní, igba ọdún ọdún kan, a ṣe ní ádùrá wípé kí bàtà ó pẹ́ lẹ́sẹ̀ àti wí pé kí o máa ṣe dáadáa síwájú síi. Dáadáa tí ó fí bẹ̀rẹ̀ náà ni kí o máa ṣe lọ láì wo ariwo ọjà.

Ó mú ìdúróṣinṣin àti òtítọ́ pẹ̀lú ìfẹ́ fún dáadáa àti ìdàgbàsókè. Gbígba igbẹkẹle náà. Ohun tí o ti mú wá sínú ìjọba jẹ́ irú igbẹkẹle tí ó dá lórí eyiti o fi agbára mú ìjá fáfá, ìfẹ́ àti ìgbẹ́kẹ̀lé. “Igbẹkẹlẹ jẹ́ ire gbogbo ènìyàn; a kò le ṣe àwọn ohun ńlá lápapò láìsí igbẹkẹle. Ṣùgbọ́n igbẹkẹle ni láti jèrè ”ó tẹnu mọ.

Láti Iléeṣẹ́ Akéde YBTC YORUBA ń kí Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkìtì kú ọjọ́ ìbí òní kí ọba Èdùmàrè báwa dáwon sí kí wọ́n ṣe ọpọlọpọ ọdún láyé