Categories
Ìròyìn

Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó Pe Àwọn Aṣòfin Tí Wọ́n Jáwe Gbéléẹ Fún Padà

YBTC News Yorùbá-Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ti pe àwọn Aṣòfin tí ó jáwe gbélé ẹ lé lọ́wọ́ ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹta ọdún yìí padà sí ilé Aṣòfin náà.

Agbẹnusọ ilé Aṣòfin náà ní ọjọ́ ọjọ́bọ kéde ìpenipadà náà ní ọjọ́ ọjọ́bọ nígbà tí Ìjíròrò ń lọ lọ́wọ́

Àwọn Aṣòfin mẹ́ta tí ọ̀rọ̀ náà kán náà ni arákùnrin Olumuyiwa Jimoh tí ó jẹ́ Igbá-kejì ọmọ ẹgbẹ́ tí ó pọ̀ jùlọ tẹ́lẹ̀ rí, arákùnrin Rotimi Abiru tí ó jẹ́ alukoro ilé Aṣòfin náà, arákùnrin Moshood Oshun àti arákùnrin Raheem Adewale.