YBTC News Yoruba—Erling Braut Haaland ti gbá bọ́ọ́lù sáwọ̀n nígbà ogójì báyìí nínú gbogbo ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí ó ti kópa nínú sáà igbábọ́ọ́lù tí ó ń lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí.
Ọ̀dọ́mọdé ẹlẹ́sẹ̀ eworo lóri pápá náà tú ṣiṣẹ́ àràmàǹdà nígbà tí Ikọ̀ rẹ̀, ìyẹn Borusia Dortmund gbojú Werder Bremen yánayàna ní ọjọ́ àbàmẹ́ta nínú ìdíje àgbákuta líígì ilẹ̀ Jamaní