Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

A Ní Atọ́ka Gbogbo Ẹni Tí ó Ní Àrùn Ibà Ìrẹ̀lẹ̀ – Ilé Ìwòsàn Ilé Ìwé Gíga Ti Ìpínlẹ̀ Èkó Ìjọba Àpapọ̀

Alága fún ìgbìmọ̀ agbani-nímọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ ìlera ní ilé ìwòsàn ilé ìwé gíga ti ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn Lagos University Teaching Hospital, ìyẹn Ọ̀jọ̀gbọ́n Wasiu Adeyemo ti sọ wípé àwọn ní atọ́ka fún gbogbo àrùn ibà Ìrẹ̀lẹ̀ ní orílẹ̀ èdè yìí.

Ó ní òun lè fọwọ́ sọ yà wípé ilé ìwòsàn náà ti ń ṣe ìtọ́jú fún ẹnìkan báyìí lórí àrùn ibà Ìrẹ̀lẹ̀ ní ìyára ìdánìkanwà tí àwọn ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀.