Categories
Ìròyìn

Ọlọ́pàá DSS Ṣèèṣì Pa Ọkùnrin Kan Nígbà Tí Ó Fẹ́ Yìnbọn Fún Màálù Kérésìmesì Tójá

YBTC Yorùbá- Ìròyìn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé Ọlọ́pàá DSS kan ti yìnbọn pa arákùnrin kan tí a mọ̀ sí Onyeocha Umuokwu ní agbègbè Alor ní ìjọba ìbílẹ̀ Gúsù Idemili ní ìpínlẹ̀ Anambra.

A gbọ́ wípé Onyeocha rí ikú oró náà re ní ọjọ́ ọdún Kérésìmesì. Bí a ṣe gbọ́, màálù bàbá olówó kan lọ́jú ní Ọlọ́pàá bá ní kí òun yìnbọn Lúù, ṣàdédé ní ìbọn bá a lọ ba arákùnrin náà ní àyè